Àwọn ènìyàn Lubimbi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àwọn ènìyàn Lubimbi wà ní oríṣiríṣi ní Africa, pàápàá jùlọ ní gúúsù Áfríkà. Àwọn orílẹ̀ èdè tí wọ́n pọ̀ sí South Africa, Zimbabwe, Mozambique, Zambia, Democratic Republic of Congo, Tanzania àti Uganda.

Ìtàn[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

The Lubimbi jẹ́ ọmọ ìran kan, ìran Mhlabawadabuka ọmọ Gasa àti àti arákùnrin Manukuza's [Soshangane]. Mhlabawadabuka ni ó dá ìran Lubimbi kalẹ̀, ó sì gbìyànjú láti gba òmìnira nípa dídá ẹ̀yà rẹ̀ kalẹ̀. Ìjàpadà Iẹ́lẹ̀ láàrin òun àti Manukuza [Soshangane], èyí mú kí wọ́n lé Manukuza kúrò láàrin wọn.[1] Ó padà dara pọ̀ mọ́ Zwangendaba àti àwọn ọmọlẹ́yìn rẹ̀ tó kù, wọ́n sì lọ kalẹ̀ sí pẹ̀tẹ́lẹ̀ Zambezi níbi tí wón ti padà pínyà ní ọdún 1834.

Ọ̀rọ̀ ajé[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ọ̀rọ̀ ajé Lubimbi dá lórí isẹ́ àgbè, àgbàdo sì ni oúnjẹ tí wọ́n ń gbìn jù. Wọ́n tún ma ń ṣe àáké àti ọkọ̀ ojú omi.

Àṣà wọn[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn ènìyàn Lubimbi ní ìmò àti ìyẹ́sí púpò fún àwọn baba ńlá wọn, wọ́n gbàgbọ́ pé oníṣègùn Ìbílẹ̀. Ayaba Ntombazi, ìyàwó Langa kaXaba àti ìyá Gasa jẹ́ Babaláwo Dókítá.

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Soga, John Henderson (1930). The South Eastern Bantu. Cambridge University Press. ISBN 9781108066822. https://books.google.com/books?id=CdT1AAAAQBAJ.