Mòsámbìk

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Mozambique)
Jump to navigation Jump to search
Republic of Mozambique
República de Moçambique
Àsìá Àmì ọ̀pá àṣẹ
Orin-ìyìn orílẹ̀-èdèPátria Amada
(formerly Viva, Viva a FRELIMO)
Olúìlú
(àti ìlú títóbijùlọ)
Maputo
25°57′S 32°35′E / 25.95°S 32.583°E / -25.95; 32.583
Èdè àlòṣiṣẹ́ Portuguese
Vernacular languages Swahili, Makhuwa, Sena
Orúkọ aráàlú Ará Mozambique
Ìjọba Republic
 -  President Armando Guebuza
 -  Prime Minister Aires Ali
Independence
 -  from Portugal June 25, 1975 
Ààlà
 -  Àpapọ̀ iye ààlà 801,590 km2 (35th)
309,496 sq mi 
 -  Omi (%) 2.2
Alábùgbé
 -  Ìdíye 2009 22,894,000[1] (54th)
 -  2007 census 21,397,000 (52nd) 
 -  Ìṣúpọ̀ olùgbé 28.7/km2 (178th)
74.3/sq mi
GIO (PPP) ìdíye 2008
 -  Iye lápapọ̀ $18.740 billion[2] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $903[2] 
GIO (onípípè) Ìdíye 2008
 -  Àpapọ̀ iye $9.897 billion[2] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $477[2] 
Gini (1996–97) 39.6 (medium
HDI (2007) 0.402 (low) (172nd)
Owóníná Mozambican metical (Mtn) (MZN)
Àkókò ilẹ̀àmùrè CAT (UTC+2)
 -  Summer (DST) not observed (UTC+2)
Ìwakọ̀ ní ọwọ́ left
Àmìọ̀rọ̀ Internet .mz
Àmìọ̀rọ̀o tẹlifóònù 258
1 Estimates for this country explicitly take into account the effects of excess mortality due to AIDS; this can result in lower life expectancy, higher infant mortality and death rates, lower population and growth rates, and changes in the distribution of population by age and sex than would otherwise be expected.

Mozambique, fun ibise Olominira ile Mozambique (Pọrtugí: Moçambique tabi República de Moçambique, pípè [ʁɛˈpublikɐ di musɐ̃ˈbiki]), je orile-ede ni apaguusuilaorun Africa to ni bode mo Okun India ni ilaorun, Tanzania ni ariwa, Malawi ati Zambia ni ariwaiwoorunt, Zimbabwe ni iwoorun ati Swaziland ati Guusu Afrika ni guusuiwoorun.

Abe Portugal ni Mozambique wa tele. Bèbè gúsù-ìlà-oòrùn Aáfíríkà ni Mozambique wa. Ó tóbi ju Portugal gan-an lọ. Àwọn ìlú tí ó wà ní bèbè Mozambique bíi Laurence Marquis (tí ó jẹ́ olú-ìlú Mozambique) àti Beira ni àwọn ọkọ̀ ojú omi ti ń gúnlẹ̀. Ọkọ̀ ojú irín ni ó so àwọn ìlú wọ̀nyí mọ́ àwọn ilẹ̀ tí ó kan Mozambique gbàngbàn. Àwọn ènìyàn tí ó wà ní Mozambique tó 7,376,000. Púpọ̀ nínú wọn ni ó jẹ́ Bantu. Púpọ̀ nínú wọn ni ó ń ṣiṣẹ́ ní South Africa níbi tí wọ́n ti ń wa ohun àlùmọ́-ọ́nni ilẹ̀ (minerals). Àwọn mìíràn ń ṣe iṣẹ́ àgbẹ̀. Wọ́n ń gbẹ òwú, kaṣú, ìrèké àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Orí ilẹ̀ pẹẹrẹ ni wọ́nm ti ń gbin àwọn wọ̀nyí. Orí òkè ni wọ́n tí ń gbin tíì (tea).

Vasco da Gama ni ó ṣe àwárí Mozambique ní 1498. Àwọn ara Portugal bẹ̀rẹ̀ síí wá sí ibẹ̀ ní nǹkan bí 1500. Mozambique sì bẹ̀rẹ̀ síí ṣe pàtàkì fún òwò ẹrú. Àwọn ilé-iṣẹ́ (companies) ni ó ń darí ilẹ̀ yìí láti 1891 sí 1942. Ọdún 1942 ni ìjọba Portugal bẹ̀rẹ̀ síí darí ilẹ̀ yìí. Ní 1960 àti 1970, Portugal kó ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọmọ ogun lọ sí Mozambique láti bá àwọn tí ó ń jà fún òmìnira jà.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Department of Economic and Social Affairs Population Division (2009) (.PDF). World Population Prospects, Table A.1. 2008 revision. United Nations. http://www.un.org/esa/population/publications/wpp2008/wpp2008_text_tables.pdf. Retrieved 2009-03-12. 
  2. 2.0 2.1 2.2 2.3 "Mozambique". International Monetary Fund. Retrieved 2009-10-01.