Jump to content

Òkun Índíà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Indian Ocean)
Òkun Íńdíà lórí àwòrán ìṣètọ́sọ́nà.

Òkun Índíà ni Òkun Eleketa ti o tobi Ju lo ni Àgbáyé lehin Òkun Atlántíkì, ati okun Pasifiki. Ni iha Iwo Orun si okun naa, ni Orile erekusu Afrika,ni iha Ila Orun si okun naa si ni apa Ila orun-Guusu orile erekusu Asia.Si ariwa okun naa ni apa guusu Asia. Orile ede ti o tobi ju lo, Ninu awon orile ede ti o wa ni iha naa ni orile ede India, nibi ti okun naa ti mu oruko, tabi ti okun naa f'oruko jo.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]