Mọ́rísì

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Mauritius)

Coordinates: 20°12′S 57°30′E / 20.2°S 57.5°E / -20.2; 57.5

Olómìnira ilẹ̀ Mọ́rísì
Republic of Mauritius

Repiblik Moris
République de Maurice
Motto: "Stella Clavisque Maris Indici"  (Latin)
"Star and Key of the Indian Ocean"
Orin ìyìn: Motherland
Location of Mọ́rísì
OlùìlúPort Louis
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaEnglish[1][2]
VernacularMauritian Creole, French, English
Orúkọ aráàlúMauritian
ÌjọbaParliamentary republic
• President
Prithvirajsing Roopun
Pravind Jugnauth
Independence 
from the United Kingdom
• Date
12 March 1968
• Republic
12 March 1992
Ìtóbi
• Total
2,040 km2 (790 sq mi) (179th)
• Omi (%)
0.05
Alábùgbé
• 2009 estimate
1,288,000[3] (151st)
• 2000 census
1,179,137
• Ìdìmọ́ra
631.4/km2 (1,635.3/sq mi) (18th)
GDP (PPP)2008 estimate
• Total
$15.273 billion[4]
• Per capita
$12,011[4]
GDP (nominal)2008 estimate
• Total
$8.738 billion[4]
• Per capita
$6,871[4]
HDI (2004) 0.802
Error: Invalid HDI value · 65th
OwónínáMauritian rupee
Ibi àkókòUTC+4 (MUT)
• Ìgbà oru (DST)
UTC+5 (2008 only)[5][6]
Ojúọ̀nà ọkọ́left
Àmì tẹlifóònù230
Internet TLD.mu

Mọ́rísì (pípè /məˈrɪʃəs/; Faransé: L’île Maurice pípè [lil mɔˈʁis], Mauritian Creole: Moris; Geesi: Mauritius), fun ibise gege bi orile-ede Olominira ile Morisi (Faransé: République de Maurice) je orile-ede erekusu lebado Afrika ni guusuiwoorun Okun Indiain, bi 900 kilometres (560 mi) ilaorunt orile-ede Madagascar. Lapapo mo erekusu Morisi, orile-ede yi na tun ni awon erekusu Cargados Carajos, Rodrigues ati Agalega Islands. Morisi je ikan ninu awon Erekusu Mascarene, pelu erekusu Fransi Réunion ni 200 km (120 mi) si guusuiwoorun ati erekusu Rodrigues ni 570 km (350 mi) si ariwailaorun.

Titi de orundun 17, awon ara Holandi ni won joba lori ibe leyin awon ara Fransi gba leyin ti awon ara Holandi ti fi sile. Awon ara Britani gba ibe nigba awon Ogun Napoleoni, ile Morisi si gba ominira lowo Britani ni odun 1968. Orile-ede Morisi je orile-ede olominira onileasofin beni o si je omo egbe Agbajo Idagbasoke Apaguusu Afrika, Common Market for Eastern and Southern Africa, Isokan Afrika ati Ajoni awon Orile-ede.

Awon ede pataki ibe ni Kreoli Morisi, Faranse ati Geesi. Geesi nikan ni ede ibise sugbon lingua franca je Creole be sini awon iwe-iroyin ati eto telifisan tun le je ni ede Farans.[7] Ni ti eya eniyan, ogunlogo awon ara ibe je ara India be sini opolopo awon omo Afrika lo tun wa nibe ati bakana bi awon omo Europe ati omo Saina die. Ohun nikan ni orile-ede Afrika nibi ti esin totobijulo ibe je esin Hindu botilejepe awon elesin Kristi ati musulumi na wa nibe sugbon ni iye kenkele.

Ìtàn[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A postcard c.1900-1910 showing the Port Louis theatre.

Morisi ko ni awon eniyan rara ki o to di pe awon oluwakiri ara Europe te ibe do ni awon odun 1600s.[8] Awon Arabu ati awako oju-omi ara Austronesia mo erekusu yi lati orundun 10.[9] Awon awako oju-omi ara Portugal koko be ibe wo ni 1507 won si ko ibujoko sibe laigbe ibe. Oko oju-omi marun ile Hollandi ti Egbe-oko Keji je fifanka kuro lona won nigba iji nla nigbati won nlo si Spice Islands won si bale si Morisi ni 1598, nitorie won fun ibe ni oruko yi fun eye Omoba Maurice ile Nassau, Alagbato ile Netherlands.[10][11]Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]