Málì

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Mali)
Jump to navigation Jump to search
Olómìnira ilẹ̀ Málì
Republic of Mali
République du Mali
Àsìá Àmì ọ̀pá àṣẹ
Motto"Un peuple, un but, une foi"
"One people, one goal, one faith"
Orin-ìyìn orílẹ̀-èdèLe Mali
"Mali"[1]
Olúìlú
(àti ìlú títóbijùlọ)
Bamako
12°39′N 8°0′W / 12.65°N 8°W / 12.65; -8
Èdè àlòṣiṣẹ́ French
Vernacular languages Bambara
Orúkọ aráàlú Ará Málì
Ìjọba Semi-presidential republic
 -  Aare Ibrahim Boubacar Keïta
 -  Alakoso Agba Modibo Keita
Ilominira latowo Fransi 
 -  Kikede September 22, 1960 
Ààlà
 -  Àpapọ̀ iye ààlà 1,240,192 km2 (24th)
478,839 sq mi 
 -  Omi (%) 1.6
Alábùgbé
 -  April 2009 census 14,517,176[2] (67th)
 -  Ìṣúpọ̀ olùgbé 11.7/km2 (215th)
30.3/sq mi
GIO (PPP) ìdíye 2008
 -  Iye lápapọ̀ $15.084 billion[3] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $1,129[3] 
GIO (onípípè) Ìdíye 2008
 -  Àpapọ̀ iye $8.774 billion[3] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $656[3] 
Gini (1994) 50.5 (high
HDI (2007) 0.371 (low) (178rd)
Owóníná West African CFA franc (XOF)
Àkókò ilẹ̀àmùrè GMT (UTC+0)
 -  Summer (DST) not observed (UTC+0)
Ìwakọ̀ ní ọwọ́ otun[4]
Àmìọ̀rọ̀ Internet .ml
Àmìọ̀rọ̀o tẹlifóònù 223

Mali, fun tonibise bi Olominira ile Mali (Faranse: [République du Mali] error: {{lang}}: text has italic markup (help)), je orile-ede tileyika ni Apaiwoorun Afrika. Mali ni bode mo Algeria ni ariwa, Nijer ni ilaorun, Burkina Faso ati Côte d'Ivoire ni guusu, Guinea ni guusu-iwoorun, ati Senegal ati Mauritania ni iwoorun. Itobi re fi die ju 1,240,000 km² lo pelu iye awon eniyan to ju egbegberun 14 lo. Oluilu re wa ni Bamako.

Mali ni agbegbe mejo be sini awon bode re ni ariwa sun de arin Sahara, nigbati agbegbe apaguusu, nibi ti opolopo eniyan ngbe, ni awon odo Niger ati Sénégal. Ise agbe ati ise apeja ni won se ju nibe. Awon ohun alumoni Mali ni wura, uraniomu, ati iyo. Mali je ikan ninu awon orile-ede to je talaka julo mi agbaye.

Present-day Mali oni fi igba kan wa ni apa awon ile obaluaye meta ti Iwoorun Afrika to n dari idunadura kiri Sahara: Ile Obaluaye Ghana, ile Obaluaye Mali (nibiti orile-ede Mali ti gba oruko re), ati Ile Obaluaye Songhai. Ni opin awon odun 1800, Mali bo sowo awon ara Fransi, o di apa Sudan Fransi. Mali gba ilominira ni 1959 lapapo mo Senegal, gege bi Ile Apapo Mali. Leyin odun kan, Ile Apapo Mali di orile-ede alominira ile Mali. Leyin igba pipe ijoba egbe oloselu-kan, ifipagbajoba ni 1991 mu ilana-ibagbepo titun jade ati idasile Mali gege bi orile-ede toseluaralu egbe oloselu-pupo.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Presidency of Mali: Symboles de la République, L’Hymne National du Mali
  2. "Mali preliminary 2009 census". Institut National de la Statistique. Retrieved January 12, 2010. 
  3. 3.0 3.1 3.2 3.3 "Mali". International Monetary Fund. Retrieved 2009-10-01. 
  4. Which side of the road do they drive on? Brian Lucas. August 2005. Retrieved 2009-01-28