Orílẹ̀-èdè Olómìnira Áràbù Sàhráwì

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Orílẹ̀-èdè Olómìnira Áràbù Sàhráwì
Sahrawi Arab Democratic Republic

الجمهورية العربية الصحراوية الديمقراطية
Al-Jumhūrīyya al-`Arabīyya aṣ-Ṣaḥrāwīyya ad-Dīmuqrāṭīyya
República Árabe Saharaui Democrática
Flag of Sahrawi Arab Democratic Republic
Àsìá
Àmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ Sahrawi Arab Democratic Republic
Àmì ọ̀pá àṣẹ
Motto: حرية ديمقراطية وحدة  (Arabic)
"Liberty, Democracy, Unity"
Orin ìyìn: Yābaniy Es-Saharā  listen
Territory claimed by the SADR, viz. Western Sahara. The majority (marked green) is currently administered by Morocco; the remainder (yellow) is named the Free Zone by SADR.
Territory claimed by the SADR, viz. Western Sahara. The majority (marked green) is currently administered by Morocco; the remainder (yellow) is named the Free Zone by SADR.
OlùìlúEl Aaiún[1]  (under Moroccan administration)
Bir Lehlou (temporary capital)
Tindouf Camps (de facto)
Tifariti (proposed new provisional capital)[2][3]
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaArabic, Spanish
Orúkọ aráàlúSahrawi
ÌjọbaNominal republic1
• President
Brahim Ghali
Abdelkader Taleb Oumar
Disputed 
with Morocco
• Western Sahara
   relinquished by Spain

November 14, 1975
• SADR proclaimed
February 27, 1976
Ìtóbi
• Total
[convert: invalid number] (83rd)
• Omi (%)
negligible
Alábùgbé
• July 2004 estimate
267 405 (182nd)
• Ìdìmọ́ra
1.3/km2 (3.4/sq mi) (228th)
Ibi àkókòUTC+0 (UTC)
Internet TLDnone3
1 The SADR government is situated in Tindouf, Algeria. They claim control of the area east of the Moroccan Wall in Western Sahara which they label the Free Zone. Bir Lehlou is within this area.
2 Area of the whole territory of (Western Sahara) claimed by SADR.
3 .eh reserved.

Orile-ede Sahrawi Arabu Olominira Toseluarailu (SADR) (Lárúbáwá: الجمهورية العربية الصحراوية الديمقراطية‎, Spánì: [República Árabe Saharaui Democrática] error: {{lang}}: text has italic markup (help)) je orile-ede ti awon die gba to fowogbaya lori gbogo agbegbe Apailaorun Sahara, amusin ile Spein tele. SADR je lilasile latowo Polisario Front ni February 27, 1976. Ijoba SADR lowolowo n joba lori agbegbe bi 20% to fowogbaya fun. O pe awon agbegbe to wa labe ijoba re ni "Agbegbe Ominira" tabi "Aaye Ainidekun." Orile-ede Morocco lo n sejoba awon agbegbe yioku to si pe ibe ni igberiko Apaguusu. Ijoba SADR gba pe awon agbegbe to wa labe ijoba orile-ede Moroko je "Agbegbe Idurolelori (Occupied Territory) " nigbati Moroko gba pe agbegbe kekere to wa labe SADR je "Aaye Idasi (Buffer Zone)."




Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]