Àngólà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Angola)
Jump to navigation Jump to search
Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Àngólà
Republic of Angola
República de Angola  (Portuguese)
Repubilika ya Ngola   (Kikongo, Kimbundu, Umbundu)
Àsìá Àmì ọ̀pá àṣẹ
'Orin-ìyìn orílẹ̀-èdèAngola Avante!  (Portuguese)
Rìnsó Àngólà

Forward Angola!

OlúìlúLuanda
8°50′S 13°20′E / 8.833°S 13.333°E / -8.833; 13.333
ilú títóbijùlọ olúìlú
Èdè àlòṣiṣẹ́ Potogí
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn (2000) 37% Ovimbundu
25% Ambundu
13% Bakongo
22% ará Áfríkà míràn
2% Mestiço
1% ará Europe
Orúkọ aráàlú Ará Àngólà
Ìjọba Orílẹ̀-èdè olómìnira ìṣọ̀kan oníàrẹ
 -  Ààrẹ João Lourenço
 -  Igbákejì Ààrẹ Bernito de Sousa
Aṣòfin Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin
Ìlómìnira
 -  látọwọ́ Pọ́rtúgàl 11 November 1975 
Ààlà
 -  Àpapọ̀ iye ààlà 1,246,700 km2 (23k)
481,354 sq mi 
 -  Omi (%) negligible
Alábùgbé
 -  2014 census 25,789,024[1] 
 -  Ìṣúpọ̀ olùgbé 20.69/km2 (199th)
53.6/sq mi
GIO (PPP) ìdíye 2011
 -  Iye lápapọ̀ $115.679 billion[2] (64k)
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $5,894[2] (107k)
GIO (onípípè) Ìdíye 2011
 -  Àpapọ̀ iye $100.948 billion[2] (61st)
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $5,144[2] (91k)
Gini (2000) 59[3] (high
HDI (2011) 0.486 (low) (148k)
Owóníná Kwanza (AOA)
Àkókò ilẹ̀àmùrè WAT (UTC+1)
 -  Summer (DST) kòsí (UTC+1)
Ìwakọ̀ ní ọwọ́ ọ̀tún
Àmìọ̀rọ̀ Internet .ao
Àmìọ̀rọ̀o tẹlifóònù +244

Àngólà, lóníbiṣẹ́ bíi Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Àngólà (Pọrtugí: [República de Angola] error: {{lang}}: text has italic markup (help), pípè [ʁɨˈpublikɐ dɨ ɐ̃ˈɡɔla];[4] Kikongo, Kimbundu, Umbundu: Repubilika ya Ngola), jẹ́ orílẹ̀-èdè kan ní apágúsù Áfríkà tó ní bodè mọ́ Namibia ní gúsù, Orílẹ̀-èdè Olómìnira Olóṣèlú ilẹ̀ Kóngò ní àríwá, àti Zambia ní ilàòrùn; ìwọ̀òrùn rẹ̀ bọ́ sí etí Òkun Atlántíkì. Luanda ni olúìlú rẹ̀. Ìgbèríko òde Kàbíndà ní bodè mọ́ Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Kóngò àti Orílẹ̀-èdè Olómìnira Olóṣèlú ilẹ̀ Kóngò.

Ìtàn[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àngólà di ileamusin Portugal ni 1884 leyin Ipade Berlin. O gba ilominira ni odun 1975 leyin ogun itusile. Ko pe leyin ilominira ni ogun abele sele lati 1975 de 2002. Àngólà ni opo alumoni ati petroliomu, be sini okowo re ti ungbera soke pelu iwon eyoika meji lati odun 1990, agaga lateyin igba ti ogun abele wa sopin. Sibesibe opagun ijaye si kere gidigidi fun opo alabugbe, be sini ojo ori ati iye ọ̀fọ̀ ọmọwọ́ ni Angola je awon eyi to buru julo lagbaye.[5]

Jeografi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Okowo[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Governo de Angola - page 89
  2. 2.0 2.1 2.2 2.3 "Angola". International Monetary Fund. Retrieved 17 April 2012. 
  3. "Gini Index". World Bank. Retrieved 2 March 2011. 
  4. This is the pronunciation in Portugal; in Angola it is pronounced as it is written
  5. (Gẹ̀ẹ́sì) Life expectancy at birth www.cia.gov (2009)