Burkina Faso
Bùrkínà Fasò
| |
---|---|
Motto: "Unité-Progrès-Justice" ("Ọ̀kan, Ìrewájú, Ìdájọ́") ("Unity, Progress, Justice") | |
Ibùdó ilẹ̀ Burkina Faso (búlù dúdú) – ní Africa (búlù amọ́lẹ̀ & àwọ̀-érú dúdú) | |
Olùìlú | Ouagadougou |
Ìlú tótóbijùlọ | olúìlú |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | Faransé |
Lílò regional languages | Mòoré, Mandinka (Bambara) |
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn (1995) | Mossi 47.9% Fulani 10.3% Lobi 6.9% Bobo 6.9% Mande 6.7% Senufo 5.3% Grosi 5% Gurma 4.8% Tuareg 3.1% |
Orúkọ aráàlú | ara Burkina Faso (tabi Burkinabè ati Burkinabe) |
Ìjọba | Orílẹ̀-èdè olómìnira oníààrẹ díẹ̀ |
• Ààrẹ | Ibrahim Traoré |
Apollinaire de Tambèla | |
Aṣòfin | Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin |
Ìlómìnira | |
• látọwó Fránsì | 5 August 1960 |
Ìtóbi | |
• Total | 274,200 km2 (105,900 sq mi) (74th) |
• Omi (%) | 0.146% |
Alábùgbé | |
• 2020 estimate | 21,510,181[1] (58th) |
• 2006 census | 14,017,262 |
• Ìdìmọ́ra | 64/km2 (165.8/sq mi) (137th) |
GDP (PPP) | 2020 estimate |
• Total | $45.339 billion |
• Per capita | $2,207[2] |
GDP (nominal) | 2020 estimate |
• Total | $16.226 billion |
• Per capita | $792[2] |
Gini (2020) | 38.9[3] medium |
HDI (2019) | ▲ 0.452[4] low · 182nd |
Owóníná | West African CFA franc[5] |
Ibi àkókò | UTC+0 |
• Ìgbà oru (DST) | kòsí |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | ọ̀tún |
Àmì tẹlifóònù | 226 |
ISO 3166 code | BF |
Internet TLD | .bf |
|
Bùrkínà Fasò ( /bərˌkiːnə ˈfɑːsoʊ/ bər-KEE-nə FAH-soh; Faransé: [buʁkina faso]) – bakanna ni kukuru bi Burkina – je orile-ede àdèmọ́àrinlẹ̀ ni iwoorun Afrika. Awon orile-ede mefa loyi ka: Mali ni ariwa, Niger ni ilaorun, Benin ni guusuilaorun, Togo ati Ghana ni guusu, ati Côte d'Ivoire ni guusuiwoorun. Oluilu re ni Ouagadougou.
Itobi re je 274,200 square kilometres (105,900 sq mi) pelu awon alabugbe to poju 15,757,000 lo. Teletele oruko re ni Órile-ede Olominira Upper Volta (Republic of Upper Volta), o je titunsoloruko si Burkina Faso ni ojo 4 Osu Kejo 1984, latowo Aare Thomas Sankara, to tumosi "ile awon eniyan anaro" ("the land of upright people") ni awon ede Mòoré ati Dioula, ti won je ede abinibi pataki nibe. "Burkina" le je, "awon eniyan olododo", lede Mòoré, ati "Faso" tumosi "ile baba eni" lede Dioula. Awon to bugbe si Burkina Faso unje pipe ni Burkinabè ( /bərˈkiːnəbeɪ/ bər-KEE-nə-bay).
Awon eniyan tedo si Burkina Faso larin odun 14,000 and 5000 SK latowo awon ode asako ni apaariwaiwoorun ibe. Abule oko bere nibe larin odun 3600 and 2600 SK. Ibi to unje arin gbongan Burkina Faso loni nigbana je kiki awon ileoba Mossi. Awon Ileoba Mossi wonyi di ibiabo Fransi ni 1896. Leyin ti o gba ilominira latowo Fransi ni 1960, orile-ede na ri iru orisirisi ijoba ko to di eyi to wa loni, orile-ede olominira oniaare die. Aare re lowo ni Blaise Compaoré.
O je omo-egbe Ìṣọ̀kan Áfríkà, Agbajo awon Orile-ede Saheli ati Sahara, La Francophonie, Agbajo Ifowosowopo Onimale ati Agbajo Olokowo awon Orile-ede Iwoorun Afrika.
Ìtàn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ìtàn kùtùkùtù
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ibi-ile ti a mo loni bi Burkina Faso t je titedo kutukutu, larin odun 14,000 ati 5000 SK, latowo awon ode asako ni apaariwaiwoorun ibe, ti awon ohun amulo won bi ihale, igbele ati oriofa won je wiwari ni 1973 latowo Simran Nijjar. Awon abule pelu awon adako bere ni arin odun 3600 ati 2600 SK. Lori bi awon ipele awon agbe se ri, o da bi pe awon abule na je adurotitisi. Ilo irin, iseamo ati okuta didan gbera larin odun 1500 ati 1000 SK.
Aloku awon Dogo wa kakiri ni Burkina Faso ni awon agbegbe ariwa ati ariwaiwoorun. Nigbakan larin orundun kedogun ati kerindinlogun, awon Dogo kuro ni agbegbe yi lati lo budo si etioke Bandiagara. Nibo miran, awon aloku ogiri giga wa ni guusuiwoorun Burkina Faso (ati ni Côte d'Ivoire), sugbon awon ti won ko won ko ti je didamo.
Loropeni ni okuta aye atijo to nibasepo mo owo wura. Ibe ni Ibi Oso Agbaye akoko ti orile-ede Burkina Faso wa.
Arin gbongan apa Burkina Faso ni opo awon ileoba Mossi, awon to lagbara julo ninu won ni ti Wagadogo (Ouagadougou) ati Yatenga. Awon ileoba wonyi je didasile ni ibere orundun ikerindinlogun latowo awon ajagun.[6]
Láti ilẹ̀àmúsìn dé ìlómìnira
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Upper Volta
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Bùrkínà Fasò
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ìṣèlú
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn agbègbè, ìgbèríko àti ìpínapá
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ológun, ọlọ́pàá àtí alábòò
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Oríilẹ̀yíyà àti ojúọjọ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Òkòwò
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ẹ̀yàìlú
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àṣà
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ẹ̀kọ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Archived copy" (PDF). Archived from the original (PDF) on 2016-12-21. Retrieved 2016-02-18.CS1 maint: archived copy as title". 16 November 2021.
- ↑ 2.0 2.1 "Report for Selected Countries and Subjects".
- ↑ "Distribution of family income – Gini index". The World Factbook. CIA. Archived from the original on 13 May 2009. Retrieved 1 September 2009.
- ↑ Human Development Report 2020 The Next Frontier: Human Development and the Anthropocene. United Nations Development Programme. 15 December 2020. pp. 343–346. ISBN 978-92-1-126442-5. http://hdr.undp.org/sites/default/files/hdr2020.pdf. Retrieved 16 December 2020.
- ↑ CFA Franc BCEAO. Codes: XOF / 952 ISO 4217 currency names and code elements Archived 7 April 2014 at the Wayback Machine.. ISO.
- ↑ Michel Izard, Moogo. L'émergence d'un espace étatique ouest-africain au XVIe siècle