Jump to content

Èdè Kóngò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Kongo language)
Kongo
Kikongo
Sísọ níÀngólà Angola
Orílẹ̀-èdè Olómìnira Olóṣèlú ilẹ̀ Kóngò Democratic Republic of the Congo
Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Kóngò Republic of the Congo
AgbègbèCentral Africa
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀7 million
Èdè ìbátan
Lílò bíi oníbiṣẹ́
Àkóso lọ́wọ́Kòsí àkóso oníbiṣẹ́
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè
ISO 639-1kg
ISO 639-2kon
ISO 639-3kon

Kikongo tabi ede Kongo je ede Bantu ti awon eya Bakongo ati Bandundu n so.

Èdè tí àwọn ènìyàn wọ̀nyí ń sọ ni Kitumba, òun ta ń pè ní Kongó ní n ǹkan ṣe pẹ̀lú àpapọ̀ àwọn èdè Bantu. Àwọn ibi tí ati n sọ èdè yìí ni: Angola, Congo, Crabon ati Zoure.

Ní àarin odún (1960) sí Ọdún (1996) àwọn tí ó n sọ èdè yìí dín díẹ̀ ni mílíọ̀nù mọ́kànlá. Àkọtọ́ èdè wọn muná dóko; ṣùgbọ́n wọn kìí lo àmì ohùn lórí gbogbo ọ̀rọ̀ wọn. Àkọtọ wọn tó wuyì yìí lo mú kí ohun èdè wọn dín kù ní lílò.

Èdè Kongo

Kongo tàbí Kikongo – ó jẹ́ èdè Bantu, àwọn ènìyàn Bakongo ni wọn ń sọ ọ́. Ààrin ilẹ̀ Afíríkà ni ó wà. Àwọn tí wọ́n ń sọ ọ́ jẹ́ mílíọ̀nù méje ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn tí wọ́n kó ní ẹrú ní ilẹ̀ Afíríkà tí wọ́n sì tà wọ́n fún America ni wọ́n ń sọ èdè yìí. Àwọn bí i mílíọ̀nù ni wọ́n ń lo èdè yìí gẹ́gẹ́ bí èdè méjì.



Kongo language