ISO 639-1

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

ISO 639-1:2002, Àwọn àmìọ̀rọ̀ fún ìṣojú àwọn orúkọ àwọn èdè Àdàkọ:-- Apá 1: àmìọ̀rọ̀ Alpha-2 ni apa kinni ISO 639 awon eseese opagun kariaye fun awon amioro ede. Apa kinni dalelori iforukosile awon amioro leta meji. Awon amioro leta meji 136 ni won je fiforukosile. Awon amioro ti won je fiforukosile je ti gbogbo awon ede agbaye koko.

Awon amioro wonyi je wuwulo kariaye lati se ikekuru ede. Fun apere:
Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]