Jump to content

ISO 3166-2

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

ISO 3166-2 ni apa opagun ISO 3166 to je titejadesiwe latowo International Organization for Standardization lati setumo àwon amioro fun awon oruko awon ipinsabe koko (f.a igberiko, agbegbe tabi ipinle) awon orile-ede ti won je siseniamioro ni ISO 3166-1. Oruko ifisise re ni Awon amioro fun isoju fun awon oruko orile-ede ati ipinlabe won - Apa 2: Amioro Ipinlabe Orile-ede. 1998 ni o koko je titejadesiwe.

Idi ISO 3166-2 ni lati fidimule opagun kariaye amioro oniletanomba kukuru ati ayasoto lati soju awon ipin amojuto awon orile-ede.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]