Èdè Kóngò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Kongo
Kikongo
Sísọ ní

Àngólà Angola
Orílẹ̀-èdè Olómìnira Olóṣèlú ilẹ̀ Kóngò

Democratic Republic of the Congo 
Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Kóngò
Republic of the Congo
Agbègbè Central Africa
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀ 7 million
Èdè ìbátan
Lílò bíi oníbiṣẹ́
Àkóso lọ́wọ́ Kòsí àkóso oníbiṣẹ́
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè
ISO 639-1 kg
ISO 639-2 kon
ISO 639-3 kon

Kikongo tabi ede Kongo je ede Bantu ti awon eya Bakongo ati Bandundu n so.

A[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Èdè tí àwon ènìyàn wònyí ń so ni Kitumba, òun ta ń pè ní Kongó ní n nkan se pèlú àpapò àwon èdè Bantu. Àwon ibi tí ati n so èdè yìí ni: Angola, Congo, Crabon ati Zoure.

Ní àarin odún (1960) sí Odún (1996) àwon tí ó n so èdè yìí dín díè ni mílíònù mókànlá. Àkotó èdè won muná dóko; sùgbón won kìí lo àmì ohùn lórí gbogbo òrò won. Àkoto won tó wuyì yìí lo mú kí ohun èdè won dín kù ní lílò.

B[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Èdè Kongo

Kongo tàbí Kikongo – ó jé èdè Bantu, àwon ènìyàn Bakongo ni won ń so ó. Ààrin ilè Afíríkà ni ó wà. Àwon tí wón ń so ó jé mílíònù méje òpòlopò àwon tí wón kó ní erú ní ilè Afíríkà tí wón sì tà wón fún America ni wón ń so èdè yìí. Àwon bí i mílíònù ni wón ń lo èdè yìí gégé bí èdè méjì.Kongo language