Abdelkader Taleb Oumar
Ìrísí
Abdelkader Taleb Omar عبد القادر طالب عمر | |
---|---|
![]() | |
Prime Minister of the Sahrawi Arab Democratic Republic | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 29 October 2003 | |
Ààrẹ | Mohamed Abdelaziz |
Asíwájú | Bouchraya Hammoudi Bayoun |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | POLISARIO |
Abdelkader Taleb Omar (Lárúbáwá: عبد القادر طالب عمر, ʿAbd āl-Qādar Ṭāleb ʿOmar) ni Alakoso Agba ti Orílẹ̀-èdè Olómìnira Áràbù Sàhráwì (SADR), ni eto bi ijoba-leyi-odi ti Polisario Front gbekale. O je yiyan si ipo na latowo Aare SADR Mohamed Abdelaziz, leyin Ipejo Gbogbo Ololugbe Kokanla to waye ni Tifariti ni ojo 29 Osu Kewa odun 2003.
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |