Àwọn Ọba Ilẹ̀ Nàìjíríà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Ìlú àti Orúkọ Oyè wọn

Abẹ́òkúta - Aláké

Adó-Èkìtì - Èwí

Àkúrẹ́ - Déjì

Arámọkọ - Alárá

Ẹdẹ - Tìmì

Ìlokò - Aloko

Ìkọ̀lé - Ẹlẹ́kọ̀lé

Ìjerò - Ajerò

Ilẹ̀-Olújìí - Jegun

Ìdànrè - Ọwá

Ìkàrẹ́ - Olúkàrẹ́

Ifọ́n - Olúfọ́n

Ifẹ̀ - Ọọ̀ni

Ìbàdàn - Olúbàdàn

Calabar - Obong

Onitsha - Obi

Ilẹ́sà - Ọwá Obòkun

Ìlá - Ọ̀ràngún

Ìlárá - Alárá

Ìjẹ̀bú-Òde - Awùjalẹ̀

Sábẹ - Onísábẹ

Ọ̀gbàgì - Ọwá

Ọ̀wọ̀ - Ọlọ́wọ̀

Oǹdó - Òsemàwé

Ọ̀yọ́ - Aláàfin

Òṣogbo - Àtàọ́ja

Ògbómọ̀ṣọ́ - Ṣọ̀hún

Òwu - Olówu

Ijàrẹ́ - Oníjàrẹ́

Ìrèlè - Ọlọ́fin

Benin - Ọba of Benin

Lagos - Ọba of Lagos

Kaduna - Emir

Kano - Emir

Ìlọ́rin - Emir

Sókótó - Saltan

Borno - Shehu

Warri - Olú

Èjìgbò - Ogìyán