Àwọn Erékùṣù Ábákò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Coordinates: 26°28′N 77°05′W / 26.467°N 77.083°W / 26.467; -77.083

Abaco
Districts of Abacos Islands
The five administrative districts of the Abacos.
Jẹ́ọ́gráfì
IbùdóAtlantic Ocean
Àgbájọ erékùṣùÀwọn Bàhámà
Ààlà1,681 km2 (649 sq mi)
Orílẹ̀-èdè
Àwọn Bàhámà Àwọn Bàhámà
ErékùṣùAbaco
Ìlú tótóbijùlọMarsh Harbour (pop. 5,728)
Demographics
Ìkún14,100 (as of 2000)
Ìsúnmọ́ra ìkún8.4 /km2 (21.8 /sq mi)
Àwọn ẹ̀yà ènìyànÀwọn aláwọ̀dúdú ~50%, Àwọn aláwọ̀funfun ~50%
Abaco Islands

Àwọn Erékùṣù Ábákò (Abaco Islands) dubule si apaariwa awon Bahama, o si ni awon erekusu gangan Abako Ninla ati Abako Kenke, lapapo mo Wood Cay kekere, Elbow Cay, Lubbers Quarters Cay, Green Turtle Cay, Great Guana Cay, Castaway Cay, Man-o-War Cay, Stranger's Cay, Umbrella Cay, Walker's Cay, Little Grand Cay, ati Erekusu Moore. Fun imojuto, awon Erekusu Abako ni marun ninu awon Ipinaye ile awon Bahama 31: Ariwa Abako, Arin Abako, Guusu Abako, Erekusu Moore, ati Hope Town. Ninu awon ilu to wa ni awon erekusu na ni Marsh Harbour, Hope Town, Treasure Cay, Coopers Town, ati Cornishtown.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]