Àwọn Ilé Ìkàwé ní Burundi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ilé ìkàwé ni ó wà ní orílẹ̀ èdè Burundi. Ilé ìkàwé gbogbogbòò orílẹ̀ èdè náà wà ní ní Bujumbura. Wọ́n sí ilé ìkàwé Yunifásítì Burundi ní ọdún 1981, wọ́n sì ṣe àfilọ́lẹ̀ rẹ̀ ní ọdún 1985.

Ilé ìkàwé gbogbogbòò orílè-èdè Burundi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ilé ìkàwé gbogbogbòò orílè-èdè Burundi jẹ́ ilé ìkàwé orílẹ̀ èdè Burundi, tí ó wà ní Bujumbura. Ẹ̀ka àṣà ti ẹ̀ka ìjọba fún ọ̀dọ́, eré ìdárayá àti àṣà ni ó da kalẹ̀ ní ọjọ́ ogún oṣù kẹsàn-án ọdún 1989 lábẹ́ ìdarí Order No. 670/1358.[1] Adarí ilé ìkàwé náà ni Marie Bernadette Ntahorwamiye.[2]

Ilé ìkàwé Yunifásitì Burundi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ilé ìkàwé Yunifásitì Burundi sí ní ọdún 1981, wọ́n si ṣe àfilọ́lẹ̀ rẹ̀ ní ọdún 1985.

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

The library contains both the library and national archives. Though in the early 1990s the collection was still not professionally organized, due to lack of staff and funding, the library has book and card catalogues and a reading room.[3]

According to the United Nations, as of 2014 approximately 61 percent of adult Burundians are literate.[4]

  1. "History". National Library of Burundi. Archived from the original on 4 February 2018. Retrieved 20 October 2016. 
  2. "Bibliotheque Nationale du Burundi". nlsahopta.nlsa.ac.za. Archived from the original on 9 March 2018. Retrieved 20 October 2016.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. Wedgeworth, Robert (January 1993). World Encyclopedia of Library and Information Services. American Library Association. p. 157. ISBN 978-0-8389-0609-5. https://books.google.com/books?id=HSFu99FCJwQC&pg=PA157. 
  4. "Adult literacy rate, population 15+ years (both sexes, female, male)". UIS.Stat. Montreal: UNESCO Institute for Statistics. Retrieved 25 August 2017.