Àwọn Yorùbá tó ń ṣòwò ẹrú gba ojú omi Atlantic

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àwọn Ẹ̀yà Yorùbá kópa tó pọ̀ nínú okoòwò ẹrú ṣíṣe gba ojú omi Atlantic, pàápàá jù lọ nípa àṣà àti ètò-ọ̀rọ̀-ajé ní ọdún 1400 sí 1900 CE.[1][2][3]

Àwọn ìlú tí Ọ̀yọ́ ń pàṣẹ lé[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Bẹ̀rẹ̀ láti ọdún 1400 síwájú, àwọn ìlú tí ìṣèjọba Ìlú Ọ̀yọ́ ń pàṣẹ fún jẹ́ kí Èdè Yorùbá di èdè ìṣèjọba káàkiri àwọn orílẹ̀-èdè kan ní ìwọ̀-oòrùn Africa.[4][5] Ní gẹ̀gẹ̀rẹ́ òpin sẹ́ńtúrì méjìdínlógún (18th century), wọn ò mójú tó àwọn jagunjagun Ọ̀yọ́ mọ́ nítorí pé kò fi bẹ́ẹ̀ sí àwọn ìlú tí wọ́n fẹ́ gbà mọ́ sábẹ́ àṣẹ Ìlú Ọ̀yọ́ .[6][7] Dípò èyí, Ọ̀yọ́ bẹ̀rẹ̀ sí ní tẹra mọ́ Okoòwò Ẹrú káàkiri àgbègbè ilẹ̀-adúláwò, pàápàá jùlọ lápá Ìwọ̀-oòrùn Afrika.[6] Europeans bringing salt arrived in Oyo during the reign of King Obalokun.[8] Nítorí gbajúmọ̀ wọn nínú Okoòwò Ẹrú, àwọn olókoòwò ẹrú Ọ̀yọ́ bẹ̀rẹ̀ sí ní bá àwọn Òyìnbó Ìlẹ̀ Europe ṣòwò ẹrú ní Porto Novo ati Whydah.[9] Ní àkókò yìí ni àwọn Ọ̀yọ́ bẹ̀rẹ̀ sí ní tá àwọn ẹrú àti àwọn ọ̀daràn tí wọ́n bá mú fún àwọn olókoòwò ẹrú láti orílẹ̀-èdè Nederland àti Portugal.[10][11]

Ipa àṣà[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ipa tí àṣà, pàápàá jù lọ kò kéré rárá, ní àfikún sí ipa tí àṣà kó nínú okoòwò ẹrú, àti nígbà tí ó ń tẹ̀síwájú, lórí oúnjẹ àti èdè ìbílẹ̀ Afrika àti àwọn òyìnbó, kíkó àṣà àwọn Yorùbá wọ̀lú fara hàn lọ́pọ̀lọpọ̀ nínú Ẹ̀sìn Yorùbá bí ó ṣe jẹyọ nínú àwọn ẹ̀sìn bíi Santería, Candomblé Ketu, àti àwọn ìbọ mìíràn.

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Pedro Funari; Charles E. Orser Jr. (2014). Current Perspectives on the Archaeology of African Slavery in Latin America (SpringerBriefs in Archaeology). Springer. p. 138. ISBN 978-1-493-9126-43. https://books.google.com/books?id=2f9MBQAAQBAJ&pg=PA108. 
  2. Toyin Falola; Ann Genova (2005). Yoruba Creativity: Fiction, Language, Life and Songs. Africa World Press. p. 134. ISBN 978-1-592-2133-68. https://books.google.com/books?id=TJ3vI7ryh8cC&pg=PA134. 
  3. Olatunji Ojo (2008). "The Organization of the Atlantic Slave Trade in Yorubaland, ca.1777 to ca.1856". The International Journal of African Historical Studies (The International Journal of African Historical Studies (Boston University African Studies Center)) 41 (1): 77–100. JSTOR 40282457. 
  4. Stride & Ifeka 1971, p. 302.
  5. Stride, George; Ifeka, Caroline (1971) (in English). Peoples and Empires of West Africa West Africa in History, 1000–1800. New York: Africana Pub. Corp.. ISBN 9780841900691. OCLC 600422166. https://books.google.com/books?id=3_VyAAAAMAAJ. 
  6. 6.0 6.1 Oliver & Atmore 2001, p. 95.
  7. Oliver, Roland; Atmore, Anthony (2001-08-16) (in en). Medieval Africa, 1250–1800. Cambridge University Press. ISBN 978-0-521-79372-8. https://books.google.com/books?id=4o-OZ5w-BmMC. 
  8. Stride & Ifeka p. 292
  9. Stride & Ifeka 1971, p. 293.
  10. Smith 1989, p. 31.
  11. Clarence-Smith, Gervase, ed (1989) (in en). The Economics of the Indian Ocean Slave Trade in the Nineteenth Century. London: Psychology Press. ISBN 978-0-7146-3359-6. https://books.google.com/books?id=9Hfl5rpXM1sC&pg=PP11.