Santería
Ìrísí
Santería tàbí Regla de Ocha tàbí La Regla Lucumi tàbí Lukumi[1][2] jẹ́ ẹ̀sìn Ọlọ́runkan ní Kàríbẹ́ánì (ní Kúbà àti Púẹ́rtò Ríkò àti Orílẹ̀òmìnira Dómíníkì). Lukumí jẹ́ èdè ilẹ̀ Santería. Lukumí jẹ́ èdè irú Yorùbá.
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Santeria Religions of the World. ReigiousTolerance.org. Retrieved 4 January 2009.
- ↑ "Lucumi Religion". New Orleans Mistic. Retrieved 4 January 2009.