Àwọn olórí ilẹ̀ Nàìjíríà ṣáájú òmìnira
Ìrísí
Àwon olórí ilè Nàìjíríà sáájú òmìnira ni:
- Sir Fredrick Lugard – Governor General (1914-1919)
- Sir Hugh Clifford - Governor General (1919-1925)
- Sir Greamer Thompson - Governor General (1925-1931)
- Sir Dona Camearan - Governor General (1931-1935)
- Sir Benard Bourdillon - Governor General (1935-1943)
- Sir Arthur Richard - Governor General (1943-1948)
- Sir John Macpherson - Governor General (1948-1958)
- Sir James Robertson- Governor General (1958-1960)
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |