Àwọn orin Amanda Black
Ìrísí
Releases | ||
---|---|---|
↙Studio albums | 4 | |
↙Singles | 5 | |
↙Music videos | 4 |
Olórin ti orílẹ̀-èdè South Africa, ìyẹn Amanda Black tí ṣàgbéjáde àwo-orin mẹ́rin, orin àdàkọ́ mọ́kànlá, àti fídíò orín méje. Ó bọ́ sí gbàgede ní ọdún 2016, lẹ́yìn tí ó gbé orin àdàkọ kan jáde, èyí tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ "Amazulu", tí wọ́n yàn fún àmì-ẹ̀yẹ lóríṣiríṣi. Àwo-orin rẹ̀ àkọ́kọ́ tí ń ṣe Amazulu gba ìwé-ẹ̀rí ìdánimọ́ lẹ́yìn ọ̀sẹ̀ méta tí wọ́n gbé e jáde. Àwọn orin Black wà lóríAmbitiouz Entertainment, Sony Music, àti AfroRockstar, èyí tí òun tìkararẹ̀ ní.
Àwọn àwo-orin rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn àwo-orin inú studio
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àkọ́lé | Àlàyé àwo-orin | Ipò lórí Peak
|
Ìgba ìwé-ẹ̀rí |
---|---|---|---|
ZA | |||
Amazulu[1] |
|
1 | RISA: 3× Platinum[2][3] |
Power |
|
1 | |
Mnyama[4] |
|
||
From My Soil To Yours |
|
— | |
"—" denotes a recording that did not chart or was not released in that territory. |
Àwọn orin àdàkọ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Gẹ́gẹ́ bíi olórí akọrin
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àkọ́lé | Ọdún | Ipò lórí Peak | Ìgba ìwé-ẹ̀rí | Àwo-orin | |||
---|---|---|---|---|---|---|---|
ZA | UK | US | |||||
"Amazulu" | 2016 | 1 | — | — | RISA: 3× Platinum[6] | Amazulu | |
"Separate" | 8 | — | — | RISA: Platinum | |||
"Kahle" | 15 | — | — | ||||
"Thandwa Ndim" | 2019 | 13[7] | — | — | Power | ||
"Egoli" | 15 | — | — | ||||
"Kutheni Nah" (featuring Kwesta) | 2019 | Mnyama | |||||
"Let It Go" | |||||||
"Mahala" | 2023 | Àdàkọ:Non-album single | |||||
"—" denotes a recording that did not chart or was not released in that territory. |
Gẹ́gẹ́ bíi akọrin tí wọ́n ṣàfihàn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àkọ́lé | Ọdún | Ipò | Ìgba ìwẹ́-ẹ̀rí | Àwo-orin | ||
---|---|---|---|---|---|---|
ZA |
UK |
US | ||||
"Sebenza"[8] (A-Reece featuring Amanda Black) |
2016 | — | — | — | Paradise | |
"Phumelela"[9] (Miss Pru featuring Amanda Black, Saudi, Sjava, LaSauce, A-Reece, Fifi Cooper and Emtee) |
15 | — | — | RISA: Platinum | Non-album single | |
"I Do" (LaSauce featuring Amanda Black) |
2017 | 1 | — | — | RISA: 2× Platinum | Broken Lipstick |
"Round & Round" (Joey B featuring Amanda Black) |
39 | — | — | Non-album single | ||
"Gaz' Lam" (Vusi Nova featuring Amanda Black) |
2018 | 20 | — | — | Non-album single | |
"Promised Land" (Yanga featuring Amanda Black) |
2019 | — | — | — | Promised Land | |
"Siyathandana" (Berita featuring Amanda Black) |
2020 | — | — | — | Songs in the Key of Love |
Ìfarahàn bíi àlejò
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àkọ́lé | Ọdún | Àwọn olórin mìíràn | Àwo-orin |
---|---|---|---|
"My Baby" | 2016 | Jaziel Brothers | Out of the Box |
"Why" | |||
"Family" | A-Reece & P-Jay | Paradise |
Àwọn fọ́nrán orin rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Gẹ́gẹ́ bíi olóri akọrin
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àkọ́lé | Ọdún | Àwọn olùdarí |
---|---|---|
"Amazulu" | 2016 | Ambitiouz Visuals / RB Films |
"Kahioile" | Ambitiouz Visuals | |
"Thandwa Ndim" | 2019 | Vanishia Kirsten |
"Egoli" | Kuda Jembe | |
"Ndizele Wena" | 2020 |
Gẹ́gẹ́ bíi akọrin tí wọ́n ṣàfihàn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àkọ́lé | Ọdún | Àwọn olùdarí |
---|---|---|
"Seb
enza" |
2016 | Ambitiouz Visuals / RB Films |
"Phumelela" (Miss Pru featuring Amanda Black, Saudi, Sjava, LaSauce, A-Reece, Fifi Cooper and Emtee) |
Ambitiouz Visuals | |
"I Do" (LaSauce featuring Amanda Black) |
2017 | |
"Promised Land" (Yanga featuring Amanda Black) |
2018 | Pilot Films |
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Amazulu by Amanda Black on Apple Music". iTunes Store. Retrieved 14 June 2017.
- ↑ "Amanda Black's album goes platinum". News24 (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 13 December 2016. Retrieved 8 April 2019.
- ↑ Base, MTV (13 December 2016). "News : amanda black is already a star; goes platinum after 3 weeks!". MTV Base. http://www.mtvbase.com/news/amanda-black-is-already-a-star-goes-platinum-after-3-weeks/ay4q0h.
- ↑ "Mnyama by Amanda Black on Apple Music". Apple Music (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 6 August 2021.
- ↑ "AMANDA BLACK RETURNS TO HER ROOTS IN NEW ALBUM ‘FROM MY SOIL TO YOURS’ OUT NOW!". Gagasi. 17 November 2023. Retrieved 12 June 2024.
- ↑ "Amanda Black 'Amazulu' goes platinum in three weeks". YoMZansi (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 11 December 2016. Retrieved 8 April 2019.
- ↑ AKA (5 April 2019). "Looks like it's only @PrinceKaybee_SA standing in our way of having the BIGGEST SONG IN THE COUNTRY .... Thank you to all compilers and fans. #JIKA #TouchMyBlood pic.twitter.com/LtMvxguzWb". @akaworldwide (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 8 April 2019.
- ↑ Siyakholwa Mrawuzeli (2 October 2016), A Reece Sebenza Ft Amanda Black, retrieved 9 April 2019
- ↑ Ambitiouz Entertainment (25 February 2017), MissPru Dj - Phumelela Ft Amanda Black, Saudi, Sjava, Sindi & Emtee (Official Video), retrieved 9 April 2019