Àwo Àlẹ̀mọ́lẹ̀

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́


Various examples of tiles

Awo Àlẹ̀mọ́lẹ̀ni ohun tí wọ́n fi àwọn èlò bí sẹ̀rámíìkì, òkúta láti ara àpáta, irin, amọ̀ tàbí díígí ṣe. [1]

Lílò rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n ma ń lo àwo àlẹ̀mọ́lẹ̀ fún ṣíse ilẹ̀, ara ilé tàbí òrùlé ṣe lọ́jọ̀. [2]

Ìrísí rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwo àlẹ̀mọ́lẹ̀ ma ní igun mẹ́rin, mẹ́ta, tàbí kí ó rí róbótó nígbà tí wọ́n bá ṣeé tán. Ìrísí rẹ̀ dá lórí bí olùpèsè rẹ̀ bá ṣe fẹ́ kí ó rí. Pàtàkì àwo Alẹ̀mọ́lẹ̀ ni kí ó ma san gbinrin. Dídán yí ni yóò mú kí ẹwà ibi tí wọ́n bá lẹ̀ẹ́ mọ́ ó yọ. [3]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Tile". The Tile Shop. Retrieved 2020-02-11. 
  2. "Bathroom Tiles - Wall & Floor Tiles". Fired Earth. Retrieved 2020-02-11. 
  3. "Wall Tiles & Wall Tiling for Kitchens and Bathrooms, Tiles UK". Tons of Tiles UK. 2019-07-17. Retrieved 2020-02-11.