Àyèọmọìlú

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Àyèọmọìlú ni ipo jije omoilu alawujo, oloselu tabi awujo onibinibi pato kan.

Ijewiwa ni ayeomoilu ninu iro adehun alawujo gbe pelu re, awon eto ati ojuse. Aṣe àyèọmọìlú ni imoye pe awon omoilu gbodo sise fun idaraju awujo won nipa kikopa ninu okowo, ise igboro, ise aladase, ati iru igbera baun lati mudara igbesiaye fun gbogbo omoilu.