Ántígúà àti Bàrbúdà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Ántígúà àti Bàrbúdà
Antigua and Barbuda
Àsìá
MottoEach Endeavouring, All Achieving
Orin-ìyìn orílẹ̀-èdèFair Antigua and Barbuda
Orin-ìyìn ọbaGod Save the Queen 1
Olúìlú
(àti ìlú títóbijùlọ)
Saint John's
17°7′N 61°51′W / 17.117°N 61.85°W / 17.117; -61.85
Èdè àlòṣiṣẹ́ Geesi
Local language Antiguan Creole
Orúkọ aráàlú Ará Ántígúà àti Bàrbúdà
Ìjọba Parliamentary democracy
under a federal constitutional monarchy
 -  Olori Orile-ede Elizabeth II
 -  Gomina Agba Rodney Williams
 -  Alakoso Agba Gaston Browne
Igbominira latowo Ileoba Aparapo
 -  Ojoodun 1 Osu Kokanala, 1981 
Ààlà
 -  Àpapọ̀ iye ààlà 440 km2 (195th)
170 sq mi 
 -  Omi (%) negligible
Alábùgbé
 -  Ìdíye 2009 85,632 (191st)
 -  Ìṣúpọ̀ olùgbé 194/km2 (57)
793/sq mi
GIO (PPP) ìdíye 2009
 -  Iye lápapọ̀ $1.522 billion[1] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $17,892[1] 
GIO (onípípè) Ìdíye 2009
 -  Àpapọ̀ iye $1.178 billion[1] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $13,851[1] 
HDI (2007) 0.868 (high) (47th)
Owóníná East Caribbean dollar (XCD)
Àkókò ilẹ̀àmùrè AST (UTC-4)
Ìwakọ̀ ní ọwọ́ left
Àmìọ̀rọ̀ Internet .ag
Àmìọ̀rọ̀o tẹlifóònù +1-268
1 God Save The Queen is the official national anthem but it is generally used only on regal and vice-regal occasions.

Ántígúà àti Bàrbúdà (pípè /ænˌtiːgwə æti bɑːɹˈbjuːdə/ (Speaker Icon.svg listen); Spani fun "atijo" ati "onirungbon") je is a twin-orile-ede erekusu-meji larin Omi-okun Karibeani ati Okun Atlantiki. O ni erekusu meji ninla ti awon eniyan ungbe be, Ántígúà ati Bàrbúdà, pelu awon erekusu kekeke melo kan (bi awon Erekusu Great Bird, Green, Guinea, Long, Maiden ati York).Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 1.2 1.3 "Antigua and Barbuda". International Monetary Fund. Retrieved 2010-04-21.