Èdè Ìrànlọ́wọ́ Káríayé
Ìrísí
Èdè Ìrànlọ́wọ́ Káríayé (international auxiliary language) (EIK tabi IAL ati auxlang ni ede geesi) tabi ede akariaye (interlanguage) je ede fun ibanisoro larin awon eniyan lati awon orile-ede otooto ti won ko ni ede abinibi kanna. Ede Iranlowo niberebere je ede lilo keji.