Èdè Afaaru

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí

Afaaru

Avar

Omo egbé àwon èdè tí wón ń pè ní Dagestanian ni eléyìí. Dangestanian yìí tún jé omo egbé fún àwon èdè tí wón ń pè ní Caucasian. Àwon tí ó ń so Caucasian yìí tó egbèrún lónà egbètà ní Caucasus ní pàtàkì ní ìpínlè Dagestan ní Rósíà àti Azerbaijan. Àkotó Cyrillic ni wón fi ko ó sílè. Òpòlopò èyà ní àdúgbò yìí ni wón ń lò wón gégé bí èdè ìsèjoba. Àwon Andi àti Dido náà wà lára àwon èyà tí ó ń lò wón.