Èdè Bàlóṣì

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Balochi
بلوچی baločî
Sísọ ní Pakistan, Iran, Afghanistan, Turkmenistan, UAE, Oman
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀ 7–8 million (1998, Ethnologue) not include Northern Balochi
Èdè ìbátan
Lílò bíi oníbiṣẹ́
Àkóso lọ́wọ́ Kòsí àkóso oníbiṣẹ́
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè
ISO 639-2 bal
ISO 639-3 variously:
bal – Baluchi (generic)
bgp – Eastern Balochi
bgn – Western Balochi
bcc – Southern Balochi
Indic script
This page contains Indic text. Without rendering support you may see irregular vowel positioning and a lack of conjuncts. More...

Omo egbé èdè tí a ń pé ní Iranian ni Bàlúsì. Àwon tí ó ń so ó tó mílíònù márùn-ún. Púpò nínú àwon tí ó ń so ó yìí ni ó wà ní Pakísítáánì (Pakistan) ní Bàlúsísítáànì (Baluchistan). Baluclistan yìí ni ìpínlè (province) tí ó wà ní apá ìwò-oòrùn jùní pakcstan. Àwon tí ó ń so èdè yìí ní Baluchistan tó múlíònù (Iran), Afuganíísítáànù (Afghanistan) àti In-índíà (India). Àkotó Lárúbáwá (Arabic) ni wón fi ko ó sílè. Àjo kan wà tí wón ń pè ní Baluchi Academy tí ó ń ń sí pé àkosílè èdè yìí páye.