Èkùrọ́

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Palm kernel within a palm fruit.

Èkùrọ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

jẹ́ kúrú inú ẹyìn ọ̀pẹ tí ó ṣe jẹ nígbà tí àgbà fọ ésan ara rẹ̀ kúrò. Ohun èlò tí ó wúlò púpọ̀ méjì ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ lò wà nínú rẹ̀. Nínú èso ẹyìn, nígbà tí a bá bo tàbí fọ pupa ara rẹ̀ kúrò ni a tó lè rí epo pupa tí a fi ń sebẹ̀. Nígbà tí a lè rí òróró nínú èkùrọ́ tí ó wà nínú ésan tí a fọ epo kúrò lára rẹ̀.[1] Ẹ̀wẹ̀, nínú èkùrọ́ yí ni wọ́n ti ń yọ Òróró, àdí àgbọn àti àdí ṣoṣo. [2] [3] Lẹ́yìn tí a bá ti yọ epo kúrò lára ẹyìn, a lè fi iya ara rẹ̀ dáná.

Àwọn itọ́ka sí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "5. PALM KERNEL OIL EXTRACTION". Home | Food and Agriculture Organization of the United Nations. Retrieved 2020-01-02. 
  2. Oil Palm FAO Agricultural Services Bulletin-148, 2002, 60pg, ISBN 92-5-104859-2
  3. "Palm kernel cake extraction and utilisation in pig and poultry diets in Ghana". Livestock Research for Rural Development. 2008-02-29. Retrieved 2020-01-02. 

Àdàkọ:Palm oil

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]