Jump to content

Èlò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Èlò ni gbogbo ohun to wa layika wa, lati afefe ti a n min, koko inu eruku tabi kikan ojo titi de ori awon irawo ninla ati galaksi. Gbogbo eya ara ni won ni elo ti won, boya won je eniyan tabi eranko tabi ogbin. Elo je gbogbo ohun to wa ni Agbalaaye.