Ìṣírò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí

Isiro

Awoyemi, Jolaoluwa

AWÓYEMÍ JOLÁOLÚWA

ÌSIRÒ

Àwon Yorùbá ní ònà tí won ń gbà se ìsirò, béè ní àti omokékeré ní àwon Yorùbá ti ń kó omo won ni ìsirò ní síse. Won yóò ni kí ó máa fi ení, èjì korin, sere bíi

Ení bí ení ni omode ńkawó

Èjì bí èjì ni àgbàlà ń tayò

Èta bi eta e jé ka tárawa lóre

Ayò tí ta náà tún jé ònà tí àwon Yorùbá fi máa ń ko ìsirò Yorùbá ni àwon ònà tí wón fi ń se ìsirò won fún àpeere “lé”, “dín”, “àádó”, “èédé”, - jé àwon ònà fún ìfilé àti ìyokúrò ìsirò won.

Apeere ìsirò Yorùbá

1 - óókan

10 - èwá

20 - ogún

21 - Òkàn lè lógún (20+1 = òkan lé ni ogún)

26 - èrìndínlógbòn (30-4 = Ogbòn dín mérin)

30 - Ogbòn

40 - Ogójì (20x2 = Ogún méjì)

60 - Ogóta (20x3 ogún méta)

100 - Ogórùn-ún (20x5) = Ogún lónà márùn-ún)

120 - Ogófà (20x6 = Ogún lónà méfà)

50 - àádóta (20 x3 = 10, éwàá dín nínú ogún méta)

200 - Igba

240 - Òjìlélúgba (40+200; Òjì = 40)

300 - Òódúnrún

340 - Òtàdín nírinwó (400-60 = òtà = 60 lógbóta)

800 - Egbèrin (igba merin 200x4)

900 - Èédégbèrún (1000-100 = Ogórùn-ún dín ni Egbèrún

1000 - Egbèrún

1600 - Egbèjo (200x8 = igba méjo

2000 - Egbèwàa (egbàá) (200x10 – igba ní ònà méwàá)

4000 - Egbàajì (2000x2)

6000 - Egbàata (2000x3)

7000 - Èédégbàárin (8000-100 = Ogórùn-ún, dín nínú Egbàárin (800)

10, 000 - Egbàarùn-ún (Egbèrùn-ún àádóta egbèrùn-ún - àádóta òké).Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]