Ìṣeìjọánglíkánì
Ìrísí
Ìṣe ìjọ Anglican (Anglicanism) je asa kan ninu Esin Kristi to ni awon ijo ti won ni ibasepo ojoun po mo Ijo ile Ilegeesi tabi iru igbagbo, isin ati ito ijo kanna.[1] Anglikani bi oro wa lati inu ecclesia anglicana, oro ede Latin igba ailaju ni bi odun 1246 to tumosi Ijo Ilegeesi (the English Church). Awon onigbagbo Iseijoanglikani ni won unje Awon Anglikani. Opo awon Anglikani ni won je omo egbe awon ijo ti won je ara Idarapo awon Anglikani kariaye.[2]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "What it means to be an Anglican". Archived from the original on 2011-08-30. Retrieved 2009-03-16. Text "Church of England" ignored (help)
- ↑ "The Anglican Communion official website - homepage". Retrieved 2009-03-16.