Ìbádọ́gba àwọn coeficient

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Ní ìmọ̀ ìṣirò, ọ̀nà ìbádọ́gba àwọn coeficient tí a ń gbà yanjú ìṣiṣẹ́ ìbádọ́gba àwọn ìkọsílẹ̀ méjì bí polynomial fún àwọn ohun ìwúlò ti a kò mọ̀. Ó gbójú lé ìdálójú pé àwọn ìkọsílẹ̀ méjì jọrawọn bákannáan

Àpẹẹre ní ìdá gidi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ká gbà wípé a fẹ́ lo partial fraction decomposition sí ìkọsílẹ̀  yìí:

À ní, a fẹ́ gbe wá sí ipò yìí:

Tí ó jẹ́ pé àwọn ìkọsílẹ̀ tí a kò mọ yí jẹ́ A, B àti C. Ìlọ́polọ́po formulas yìí pẹ̀lú x(x − 1)(x − 2) sọ méjèèjì di àwọn  polynomial méjì, tí ó bára dọ́gba: