Ìbọ̀sẹ̀

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
A hand-knitted sock
Argyle socks

Ìbọ̀sẹ̀ ni aṣọ pélébé kan tí a rán ní dédé ìwọ̀n tí ẹsẹ̀ lè gbà tí kò sì gùn ju dédé kókósẹ̀ lọ. S ma ń eọ ìbọ̀sẹ̀ sí ẹsẹ̀ nígbà tí a bá wọ irúfẹ́ àwọn bàtà kan kí ó lè jẹ́ kí ìrìn ẹni ó lè já geere. Ní ayé àtijọ́, awọ ẹran ni wọ́n ma ń wọ̀ sí ẹsẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ìbọ̀sẹ̀.

Ìwúlò Ìbọ̀sẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ìbọ̀sẹ̀ wúlò púpọ̀ nítorí bí ó ṣe ma ń báni nígbà tí a bá wọ bàtà, pàá pàá jùlọ ó ma ń gba àágùn sára gẹ́gẹ́ bí a ti mọ̀ wípé ọ̀pọ̀ ìgbà ni ẹsẹ̀ ma ń sun àágùn nígbà tí a bá ń rìn. [1]

Striped, hand-knit socks

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Howstuffworks "Why do feet stink?"". Health.howstuffworks.com. Retrieved 2010-03-05.