Ìdíje Àgbábuta Bọ́ọ̀lù-Àfẹsẹ̀gbá tí orílẹ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì
Ìdíje Àgbábuta Bọ́ọ̀lù-Àfẹsẹ̀gbá tí orílẹ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì tí ògbufọ̀ rẹ̀ lédè Gẹ̀ẹ́sì jẹ́ English Premier League, EPL jẹ́ ìdíje Bọ́ọ̀lù Àfẹsẹ̀gbá tí ó ga jùlọ lorílẹ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì tí ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá okòó (20) máa ń díje fún lọ́dọọdún. Ó jẹ́ okowò pàtàkì lórílẹ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì tí gbogbo ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá ní ipin-ìdókowò. Ìdíje yìí máa ń bẹ̀rẹ̀ ní oṣù kẹjọ, ó sì máa ń parí ní oṣù karùn-ún ọdún tó tẹ̀ lé. Odidi ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ méjìdínlógójì ló máa ń wáyé láàrin àwọn ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá okòó.[1] Lọ́pọ̀ ìgbà, ọjọ́ Àbámẹ́ta àti ọjọ́ Àìkú ni ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ láàárín àwọn ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá wọ̀nyí máa ń wáyé. Ṣùgbọ́n nígbà mìíràn, ó máa ń wáyé láwọn ọjọ́ mìíràn. Ẹgbẹlẹmùkẹ́ owó ilẹ̀ Òkèrè ni wọ́n máa ń rí nínú ìdíje yìí, pàápàá jùlọ nínú ìṣàfihàn rẹ̀ lórí ẹ̀rọ tẹlifíṣàn káàkiri gbogbo àgbáyé.[2] The deal was worth £1 billion a year domestically as of 2013–14, with Sky and BT Group securing the domestic rights to broadcast 116 and 38 games respectively.[3] [4]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ When will goal-line technology be introduced? Archived 9 July 2013 at the Wayback Machine. The total number of matches can be calculated using the formula n*(n-1) where n is the total number of teams.
- ↑ "United (versus Liverpool) Nations". The Observer. 6 January 2002. http://observer.guardian.co.uk/osm/story/0,,626773,00.html. Retrieved 8 August 2006.
- ↑ Gibson, Owen (13 June 2012). "Premier League lands £3bn deal". The Guardian. https://www.theguardian.com/media/2012/jun/13/premier-league-tv-rights-3-billion-sky-bt/. Retrieved 14 June 2012.
- ↑ "Top Soccer Leagues Get 25% Rise in TV Rights Sales, Report Says". Bloomberg. Retrieved 4 August 2014