Ìfómipamọ ti Lagdo
Ìfómipamọ ti Lagdo | |
---|---|
Location | North Province (Cameroon) |
Coordinates | 8°53′N 13°58′E / 8.883°N 13.967°ECoordinates: 8°53′N 13°58′E / 8.883°N 13.967°E |
Lake type | reservoir |
Primary inflows | Benue River |
Primary outflows | Benue River |
Basin countries | Cameroon |
Built | 1977–1982 |
Surface area | 586 km2 (226 sq mi) |
Ifómipamọ ti Lagdo jẹ Ìfómipamọ to wa ni apa ariwa ti ilẹ Cameroon ni ódó Benue ni Basin ti Niger. Àdàgun naa bo area ti 586 km2[1].
Ìtan
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ìfomipamọ Lagdo ni a kọ lari óṣu August ọdun 1977 ati óṣu July ọdun 1982 lati ọwọ óṣiṣè Ilẹ china, engineer ati labira Cameroon[2]. Ilè iṣẹ to mojuto ìṣẹ naa ni China International Water & Electric Corp. Ìlè iṣẹ ina agbaye AES corporation lo dari Ìfómipamọ naa[3].
Idasilẹ Ifómipamọ naa da lori fifa ina si apa ariwa órilẹ ede naa ati fifun oun ọgbin ni omi lati isalẹ[4]. Ifómipamọ naa ga pẹlu 308m, 40m ni height ati 9m ni titobi. Iṣẹ Ìfómipamọ naa bẹrẹ sini dinku ni ọdun 2021 pẹlu alafo 1.6 billion m3[5].
Àgbègbè
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ìfómipamọ naa wa ni ila oorun ti Garoua ni odo Benue. Ifópamipọ naa wa ni Arrondissement de Lagdo ni Département de la Benoué ni apa ariwa[6]. Àgbègbè rẹ ni 8°53′N 13°58′E.
Ìkun omi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ni ọdun 2012, omi yaa lati Ìfómipamọ Lagdo lọsi ipinlẹ Adamawa ni ilẹ Naijiria eyi lo fa iku èniyan mẹwa ati ipadanu dukiya bi ẹgbẹrun dollar. Ipa ikun ómi yii pọ ni isalẹ Odo Benue nibi ti ilè bi ẹgbẹrun lọna mẹwa ṣofo. Eyi lo mu ki ókó hectares bi ẹgbẹrun lọna mẹwa kun fun ómi ti agbègbè Makurdi si kun fun awọn ẹranko buruku bi Ọọni[7].
Ni óṣu September, ọdun 2022, igbiyanju bẹrẹ̀ lati ko ninu omi ti Ìfomipọ Lagdo ni ọna lati tunṣè[8]. Awọn alakoso Naijiria ti fi lọlẹ pe omi to wa lati Lagdo ti pa aimoye ókó run to si jasi ikun omi to lagbara ni ipinlẹ mẹtala[9], eyi lo fa iku eniyan maarun dinlogun ni ipinlẹ Adamawa[10]. Ṣugbọn Minister lori akoso ómi Suleiman Adamu Kazaure sọpe pupọ ninu ikun omi to ṣẹlẹ wa latari ójó[11].
Aini Ìfómipamọ lati mu ómi lati ìfómipamọ Lagdo jẹ ọkan gbogi ninu oun ti o fa ikun òmi ni ilẹ Naijiria[12].
Awọn Itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Abdullahi, Idowu (2023-08-29). "Flood: Seven facts about Cameroon's Lagdo dam". Punch Newspapers. Retrieved 2023-09-09.
- ↑ Ngounou Ngatcha, Benjamin; Njitchoua, Roger; Naah, Emmanuel (2018-11-06). "Le barrage de Lagdo (Nord-Cameroun)" (in Èdè Faransé). IRD Éditions. Retrieved 2023-09-09.
- ↑ Omigbodun, Akintola (2013-07-02). "Cameroon, the River Benue and Nigeria". Vanguard News. Retrieved 2023-09-09.
- ↑ Imokhai-Bello, Ishioma (2022-10-21). "Lagdo Dam: How Nigerians are paying for the irresponsibilities of past governments". Ventures Africa. Retrieved 2023-09-09.
- ↑ Ecofin, Agence. "Cameroun : le barrage de Lagdo perd 3 milliards m3 d’eau en deux ans (gouvernement)". Agence Ecofin (in Èdè Faransé). Retrieved 2023-09-09.
- ↑ Omorogbe, Paul; Omorogbe, Paul (2022-10-10). "Nigeria’s perennial flooding and effect of Cameroon’s Lagdo Dam". Tribune Online. Retrieved 2023-09-09.
- ↑ "Disaster: Warning about impending flood – Blueprint Newspapers Limited". Blueprint Newspapers Limited. 2018-05-23. Retrieved 2023-09-09.
- ↑ M, Rachel (2022-09-14). "Barrage de Lagdo : Eneo va relâcher une partie des eaux". ÔCamer.com (in Èdè Faransé). Retrieved 2023-09-09.
- ↑ Mom, Claire (2022-09-20). "NEMA: 13 states to record heavy flooding as Cameroon opens Lagdo dam". TheCable. Retrieved 2023-09-09.
- ↑ Reporters, Our (2022-09-21). "Flood kills 25, displaces 130,200 in Adamawa, Plateau". Punch Newspapers. Retrieved 2023-09-09.
- ↑ Chime, Vivian (2022-10-20). "80% of floods caused by rainfall NOT Lagdo dam, says minister". TheCable. Retrieved 2023-09-09.
- ↑ "Quick facts about Cameroon's Lagdo Dam causing floods in Nigeria". The Nation Newspaper. 2022-10-18. Retrieved 2023-09-09.