Ìgbéríko Àrin (Kẹ́nyà)

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ìgbéríko Àrin
Location in Kenya.
Location in Kenya.
Country Kenya
No. of districts:12
CapitalNyeri
Area
 • Total13,191 km2 (5,093 sq mi)
Population
 (2007)
 • Total4,145,000
Time zoneUTC+3 (EAT)
Central Province of Kenya surrounds its capital, Nyeri, and includes slopes of Mount Kenya (click to enlarge map).

Ìgbéríko Àrin Kenya ni agbegbe 'keta to o kere ju lo ni Orile Ede Kenya, lehin agbegbe Nairobi, ati agbegbe Iwo Oorun, pelu Àpapọ̀ iye ààlà 13,191 km2 (5,093.1 sq m).agegbe naa wa ni iha Ariwa si ilu Nairobi, ati iha Iwo O'orun si oke Kenya. Ni Ikaniyan to odun 2009, agbegbe naa ni iye eniyan Olùgbé 4,383,743. Olu ilu agbegbe naa ni ilu Nyeri.Agbegbe aarin Kenya je Ile isenbaye ti awon eya Kikuyu.

Kilimati[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

kilimati Agbegbe aarin Kenya ni akoto tutu ju awon agbegbe iyoku orile Ede naa lo, nitori wipe, agbegbe naa wa no ile giga ju awon agbegbe 'yoku lo.Ojo maa n ro ni asiko meji ninu Odun. L'akoko lati osu Iketa(March), so osu karun-un(May), ati asiko elekeji to o bere ni Osu Kewaa(october} ati osu Ikakanla(November). Awon ojo akoko elekeji wonyii ni a mo si awon ojo asiko kukuru

Imo akoto[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]