Ìjàyè

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Ìjàyè jẹ́ ìlú kan tí ó lágbára pupọ̀ láàrín àwọn ìlú àti ilẹ̀ Ọba ní ilẹ̀ Yorùbá. Ìlú Ìjàyè wà ní ara àwọn ìlú tí àwọn ọmọ Yorùbá tí wọ́n ságun ní Ọ̀yọ́-Ilé sá sí nígbà tí ogun àwọn Fúlàní kó ìlú Ọ̀yọ́-Ilé ní ọdún 1836.Ẹni tí ó jẹ́ adarí àti alákòóso ìlú náà ni Ààrẹ Kúrunmí[1]


Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]