Ìkẹ́kọ́ Òkèrè

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ìkẹ́kọ̀ọ́ Òkèrè ìlànà ìkẹ́kọ̀ọ́ yí wà fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tí ọ̀nà wọn jìn, tí wọ́n sì kò sì ní ànfàní láti dara pọ̀ mọ́ àwọn akẹgbẹ́ wọn nílé ẹ̀kọ́. Ìlànà ìkẹ́kọ̀ọ́ yí ma ń dá lé fífi àwọn àkóónú, kókó, àti àwọn àtúpalẹ̀ ẹ̀kọ́ gan an ránṣẹ́ sí akẹ́kọ̀ọ́ ní ibi kíbi tí ó bá wà lórílẹ̀ àgbáyé, nípa lílo àpò ìfìwé -ránṣẹ.́  Àmọ́, láyé ode òní, ìlànà Ìkíniẹ́kọ̀ọ́ yí ti gbọ̀nà ará ọ̀tọ̀ nípa kíkẹ́kọ̀ọ́órí ẹ̀rọ ayélujára. [1] Ikẹ́kọ̀ọ́ òkèrè lè jẹ́ alásínpọ̀ tí akẹ́kọ̀ọ́ yóò ma kẹ́kọ̀ọ́ láti ọ̀nà jíjìn tí yóò sì tún ní ànfàní láti dara pọ̀ mọ́ àwọn akẹgbẹ́ rẹ̀ nínú iyàrá ìkẹ́kọ̀ọ́.[2][3]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Tabor, Sharon W (Spring 2007). "Narrowing the Distance: Implementing a Hybrid Learning Model". Quarterly Review of Distance Education (IAP) 8 (1): 48–49. ISBN 9787774570793. ISSN 1528-3518. https://books.google.com/books?id=b46TLTrx0kUC. Retrieved 23 January 2011. 
  2. Kaplan, Andreas M.; Haenlein, Michael (2016). "Higher education and the digital revolution: About MOOCs, SPOCs, social media, and the Cookie Monster". Business Horizons 59 (4): 441–50. doi:10.1016/j.bushor.2016.03.008. 
  3. Honeyman, M; Miller, G (December 1993). "Agriculture distance education: A valid alternative for higher education?". Proceedings of the 20th Annual National Agricultural Education Research Meeting: 67–73. http://files.eric.ed.gov/fulltext/ED366794.pdf#page=80.