Ìlárá-Mọ̀kín jẹ́ ìlú ẹ̀yà Èkìtì tó wa nínú àgbègbè-ìjọba ní ìpínlẹ̀ Òǹdó. Ìlárá-Mọ̀kín súnmọ́ àwọn ìlú bí Àkúrẹ́, Ìpogun, Ìkọta, Èró, Ìgbàrà-Okè, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ́. Wọ́n sọ ẹkà-èdè Yorùbá tó jẹ́ "èdè Èkìtì"