Ìmúdọ́gba Àyipàdà Ójú Ọjọ́

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àṣamubadọgba Lori Àyipada Óju Ọjọ jẹ ọna a ti ṣè àtunṣè lori ipa ayipada óju ọjọ. Èyi jẹ ipa ti oun ṣẹlẹ lọwọ tabi eyi to nbọ. Àṣamubadọgbà jẹ ọna lati dinku tabi dina abùrù kuró fun ọmọ èniyan. Èyi jẹ ọnà fun ọpọlọpọ anfani, èniyan ni lati dasi ọrọ ayipada ójù ọjọ. Óriṣiriṣi àgbèkalẹ ati ètó lo wa ni Àṣamubadọgba lati dina aburu tabi ipa awọn ìṣẹ̀lẹ̀ yii[1][2][3].

Ìdi fun Àṣamubadọgba gbẹ̀kẹlè agbègbè kan si ìkèji. Èyi lè jẹ abùrù fun èniyan tabi ayika. Àṣamubadọgba ṣè pataki fun awọn órilẹ èdè to ti dàgbà sókè nitori awọn lo maa nfarapà julọ ninu ayipada ójù ọjọ nitori idi èyi wọn maa kóju ipà ìṣẹlẹ naa. Àṣamubadọgba tobi fun ounjẹ, ómi, ọrọ àjè, iṣẹ tabi ówó ójọ[4][5].

Ìgbaradi ati ètó fun Àṣamubadọgba ṣè pataki órilẹ èdè lati koju abùrù to wa ni ayipàdà ójù ọjọ. Èyi ló mu ki ipèlè ijọba lati óriṣiriṣi agbègbè ṣè agbèkalẹ ètó. Awọn órilẹ ede to ti dagbàsókè maa nwa ówó lati ókè ókun ni ọna lati ṣè agbèkalẹ ètó lati ṣiṣẹ lóri Àṣamubadọgba. Ètó yii ni lati mujutó awọn ifarapa tabi èwù tolè ṣuyọ latari ayipadà ójù ọjọ. Iye owo Àṣamubadọgba ayipàdà óju ọjọ jẹ billionu dollar lọdọdun fun ọdun mẹwa to nbọ. Fun ọpọlọpọ igba, Iye owo naa dinku si bibajẹ to fẹ̀ ṣiṣẹ lori.[6].

Ìwadi lori Àṣamubadọgba àyipàdà ójù ọjọ bẹrẹ lati ọdun 1990s. Óriṣiriṣi ọrọ lori rẹ losi ti lèkun lati igbànà. Àṣamubadọgba di ófin to mulẹ ni ọdun 2010s lati igba adehun ilẹ Paris to si sọdi ọrọ pataki fun iwàdi ófin[7][8]. Ìwadi ijinlẹ sayẹnsi lori Àṣamubadọgba ayipàdà ójù ọjọ bẹrẹ pẹlù Ìtu si wẹwẹ ìpa ayipada óju ọjọ lori eniyàn, àyikà ati Ìlànà ìbáṣepọ̀ àwọn ohun ẹlẹ́mìí pẹ̀lú àyíká. Awọn Ipà nàà bóri ìṣẹmi, ètó iwósan ati àyika. Ìpayi lè jẹ ayipàdà ìkórè oun ọgbin, àlèkun ìkun ómi ati ọ̀gbẹlẹ. Ìtu si wẹwẹ awọn ipa yii jẹ ọna pataki lati mọ Àṣamubadọgba ti ọjọ iwaju[9].

Awọn àgbèkalè lati dina èwù to wa ninu àyipada ójù ọjọ[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Gẹ̀gẹbi ajọ IPCC, Ipalara ayipàdà ójù ọjọ jẹ̀ ọpọlọpọ ọna to lè jàsi èwù ati aini àgbara lati ṣè àfàràdà. Ó ṣee ṣe lati dinku èwù ni àgbègbè pẹlu fifi alawọ ewe ọgba sibẹ̀. Èyi ló dinkù óórù ati aini óunjẹ ni awọn ilu ólówó kèkèrè. Ọkan làrà ọna lati dinkù èwu ójù ọjọ ni Àṣamubadọgba Ìlànà ìbáṣepọ̀ àwọn ohun ẹlẹ́mìí pẹ̀lú àyíká. Fun àpẹrẹ, awọn ìgì to wa lèti òmi ni àgbàra lati dèna ìjì eyi lo mu ki wọn lè dèna ìkùn ómi. Ìdàbóbó igi èti ómi ni àyika jẹ ọna kan gbogi làti ṣè Àṣamubadọgba. Awọn ọna miran ni idàbóbó awùjó ati dida óhun amaàyedẹrun to lè kóju èwù silẹ[10].

Àtunṣè Wetland ni ilẹ Australia

Èsi Àṣamubadọgba pinsì àbàlà mẹrin lati dinkù èwu eyi to mù ónirùrù anfààni dani; Àṣamubadọgba ohun àmàyèdẹrun, ófin ati ilànà ijọba, àgbèkalẹ fun awùjọ ati ilè óriṣiriṣi pẹ̀lù Àṣamubadọgba Ìlànà ìbáṣepọ̀ àwọn ohun ẹlẹ́mìí pẹ̀lú àyíkà[11].

Wiwó awọn ẹlegbẹgbẹ to wa ni Monterey County strawberry, Órilẹ èdè U.S

Órìṣiriṣi ọna lowa, eyi jẹ ṣiṣè àgbèkàlẹ ohun amàyèdẹrun lati dèna óóru, ikun ómi, alèkun ninu ipèlè ódó, ohun amayèdèruj lati kóju ayipàdà ójó ninu iṣẹ ohun ọgbin. Ohun amayèdẹrun lati fa ómi si inu ókó latari ọgbẹ̀lẹ̀[12].

Ètó ati àgbèkalè lati tun ómi to wa ni ókó Woodbury County ṣè ni àríwá ìwọ̀ oòrùn Iowa, Órilẹ èdè U.S

Óunjẹ bibajẹ maa lèkun pẹlù óóru ati ìṣẹlẹ ìkun ómi. Èyi jẹ èwù fun Ounjẹ aabo ati jijẹun. Ìwọn Àgbèkalẹ̀ Àṣamubadọgba wa lati wó èrè ókó lati ọdọ awọn àgbẹ gẹgẹbi ṣiṣa èrè ókó to ba ti bàjẹ sọtọ tabi sisa awọn èrè ókó ki wọn lè gbẹ eyi lo ma dinku èwù bibajẹ. Awọn Àṣamubadọgba miran jẹ gbigba awọn èsó ti ko dàrà lọ titi, ìpin óunjẹ to ba ti pọju ati ìdinku iyè ounjẹ to ba ti fẹ bajẹ̀ fun awọn to ma tawọn ati rawọn lọja[13].

Ágbèkalẹ Iṣẹ ni Àgbègbè Ètikun ni Quelimane, ilẹ Mozambique. Eyi jẹ ọna lati ṣè igbaradi ilẹ Quelimane fun iṣẹlẹ àyipada ójù ọjọ bi ìkun ómi, Àkúnjù omi òkun ati ọgbàrà

Àyipada óunjẹ pẹlù jijẹ awọn óunjẹ to wa lati óun ọgbin yatọsi ti ẹran nitori awọn oun ọgbin niló agbara kèkèrè ati liló ómi ti kó pọ rara. Awọn ófin to gbèjà awọn óunjẹ yi jẹ ọna lati ṣè iwùló fun Àṣamubadọgba.Óun ọgbin pèsè óriṣiriṣi ọna fun Àṣamubadọgba, eyi jẹ̀ ayipàdà ninu igba gbingbin tabi àyipada oun ọgbin ati ẹ̀ran ọsin to ba igbà ójù ọjọ mu to si lè kóju awọm kókóró àjẹnirun. Èyi lo jẹ̀ ọna lati ṣè idabóbó óunjẹ̀[14][15][16].

Awọn Ìtọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "AR6 Climate Change 2022: Impacts, Adaptation and Vulnerability". IPCC. 2022-02-27. Retrieved 2023-09-27. 
  2. "Unprecedented Impacts of Climate Change Disproportionately Burdening Developing Countries, Delegate Stresses, as Second Committee Concludes General Debate". UN Press. 2019-10-08. Retrieved 2023-09-27. 
  3. Sarkodie, Samuel Asumadu; Ahmed, Maruf Yakubu; Owusu, Phebe Asantewaa (2022-04-05). "Global adaptation readiness and income mitigate sectoral climate change vulnerabilities". Humanities and Social Sciences Communications (Springer Science and Business Media LLC) 9 (1). doi:10.1057/s41599-022-01130-7. ISSN 2662-9992. 
  4. Environment, UN (2021-01-14). "Adaptation Gap Report 2020". UNEP - UN Environment Programme. Retrieved 2023-09-27. 
  5. Klein, Richard J. T.; Siebert, Clarisse Kehler; Davis, Marion; Dzebo, Adis; Adams, Kevin M. (2017-05-22). "Advancing climate adaptation practices and solutions: emerging research priorities". SEI. Retrieved 2023-09-27. 
  6. Adaptation Committee, 2021, Approaches to reviewing the overall progress made in  achieving the global goal on adaptation
  7. "The Paris Agreement". unfccc.int. Retrieved 2023-09-27. 
  8. O'Neill, B., M. van Aalst, Z. Zaiton Ibrahim, L. Berrang Ford, S. Bhadwal, H. Buhaug, D. Diaz, K. Frieler, M. Garschagen, A. Magnan, G. Midgley, A. Mirzabaev, A. Thomas, and R.Warren, 2022: Chapter 16: Key Risks Across Sectors and Regions. In: Climate Change 2022: Impacts, Adaptation and Vulnerability. Contribution of Working Group II to the Sixth Assessment Report of the Intergovernmental Panel on Climate Change [H.-O. Pörtner, D.C. Roberts, M. Tignor, E.S. Poloczanska, K. Mintenbeck, A. Alegría, M. Craig, S. Langsdorf, S. Löschke, V. Möller, A. Okem, B. Rama (eds.)]. Cambridge University Press, Cambridge, UK and New York, NY, USA, pp. 2411–2538,doi|10.1017/9781009325844.025
  9. "Special Report on the Ocean and Cryosphere in a Changing Climate —". IPCC. 2022-03-01. Retrieved 2023-09-27. 
  10. Jellason, Nugun P.; Salite, Daniela; Conway, John S.; Ogbaga, Chukwuma C. (2022). "A systematic review of smallholder farmers’ climate change adaptation and enabling conditions for knowledge integration in Sub-Saharan African (SSA) drylands". Environmental Development (Elsevier BV) 43: 100733. doi:10.1016/j.envdev.2022.100733. ISSN 2211-4645. 
  11. Solecki, William; Friedman, Erin (2021-04-01). "At the Water's Edge: Coastal Settlement, Transformative Adaptation, and Well-Being in an Era of Dynamic Climate Risk". Annual Review of Public Health (Annual Reviews) 42 (1): 211–232. doi:10.1146/annurev-publhealth-090419-102302. ISSN 0163-7525. 
  12. "Managing the Risks of Extreme Events and Disasters to Advance Climate Change Adaptation". IPCC. 2023-09-18. Retrieved 2023-09-27. 
  13. Kelman, Ilan; Gaillard, J C; Mercer, Jessica (2015). "Climate Change’s Role in Disaster Risk Reduction’s Future: Beyond Vulnerability and Resilience". International Journal of Disaster Risk Science (Springer Science and Business Media LLC) 6 (1): 21–27. doi:10.1007/s13753-015-0038-5. ISSN 2095-0055. 
  14. "Food security threatened by sea-level rise". Nibio (in Èdè Norway). 2015-02-17. Retrieved 2023-09-27. 
  15. Rosenzweig, Cynthia; Mbow, Cheikh; Barioni, Luis G.; Benton, Tim G.; Herrero, Mario; Krishnapillai, Murukesan; Liwenga, Emma T.; Pradhan, Prajal et al. (2020-02-18). "Climate change responses benefit from a global food system approach". Nature Food (Springer Science and Business Media LLC) 1 (2): 94–97. doi:10.1038/s43016-020-0031-z. ISSN 2662-1355. 
  16. Lucas, Anthony (2013-08-18). "Coastal cities face rising risk of flood losses, study says". Phys.org. Retrieved 2023-09-27.