Jump to content

Ìpájà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ìpájà jẹ́ ìlú kan tí ó kalẹ̀ sí Ìlú Èkó ní abẹ́ àṣẹ ìjọba ìbílẹ̀ Alímọ̀ṣọ́.[1]Ìlú náà tobi púpọ̀ tí ósì fi àyè gba ọ̀gọ̀rọ̀ ènìyàn tí wọ́n jẹ́ olùgbé yálà ọmọ ìlú tàbí ààrè. Oríṣiríṣi ilé ìgbafẹ́ àti ìtura ló wà ní ìlú náà pẹ̀lú.[2]

Àwọn Ìtọ́ksí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Ipaja, Lagos, Nigeria Three Day Weather Forecast". AccuWeather. 2019-12-14. Retrieved 2019-12-14. 
  2. "Ipaja Map". Nigeria Google Satellite Maps. Retrieved 2019-12-14.