Ìpéjọlunipa ní Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
John Wesley Heath jẹ́ pípébò pa ní Tombstone, Arizona ni February 22, 1884 fún ìkópa rẹ̀ nínú Bisbee Massacre.

Ìpéjọlunipa (Lynching), ìwà pípéjọ pa ènìyàn láìsí ìdájọ ṣẹlẹ̀ ní Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà láyi òpin ọ̀rúndún 18k títí dé ìgbà àwọn ọdún 1960. Ìpéjọlunipa ṣẹlẹ̀ gidigidi ni Apágúúsù Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà láti 1890 dé àwọn ọdún 1920, pẹ̀lú 1892 bíi ọdún tó ṣẹlẹ̀ jùlọ. Bákannáà, ìpéjọlunipa náà tún wọ́pọ̀ ní Agbègbè Ìwọ̀òrùn.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]