Jump to content

Ìpínlẹ̀ Ìlàòrùn-Àrin

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ipinle East Central je ipinle amojuto tele ni Nigeria. O je dida ni 27 May 1967 lati awon apa Agbegbe Apailaorun o si wa titi di 3 February 1976, nigbati o je pinpin si ipinle meji - Anambra ati Imo. Loni awon ipinle marun ni won wa nibi to wa tele: Anambra, Imo, Enugu, Ebonyi ati Abia. Ilu Enugu ni o je oluilu re nigbana.

Awon Gomina/Olumojuto Ipinle East Central[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]