Jump to content

Ìsìnrú gbèsè

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ìsìnrú gbèsè ni jíjẹ́ ẹ̀jẹ́ láti ṣiṣẹs fún èlò míràn án láti dógò fún gbèsè tí ènìyàn jẹ ẹlòmíràn. Èyí mú kí ẹni tí ó ya ìkejì lọ́wọ́ wà ní àkóso ẹnikejì títí di ìgbà tí ó ma rí owó náà ṣan.[1] The services required to repay the debt may be undefined, and the services' duration may be undefined, thus allowing the person supposedly owed the debt to demand services indefinitely.[2] Wọ́n le sìrún gbèsè láti iran kan sí òmíràn.[2]

Lọ́wọ́ lọ́wọ́, ìsìnrú gbèsè jẹ́ gbọ́gì lára àwọn ọ̀nà tí wọ́n fi kó àwọn ènìyàn lẹ́rú pẹ̀lú àwọn ènìyàn tí ó lé ní mílíọ̀nù mẹjọ lábé ìsìnrú yìí ní ọ̀nà tí kò tó gẹ́gẹ́ bí International Labour Organization ṣe sọ ní ọdún 2005.[3]

Àṣà ìsìnrú yìí sì wọ́pọ̀ ní ìwọ̀ gúúsù Asia àti apá díè nínú ìwọ̀ oòrùn àti gúúsù Áfríkà. Ìdásí mẹjọ nínú mẹ́wàá àwọn tí ó wà nínú ìsìnrú ní South Asia wà lábé ìsìnrú gbèsè.[4][5] Àìbá àwọn tí ó ń kó ènìyàn lẹ́rú lọ́nà yìí wí jẹ́ ọ̀kan lára ìdí tí ìsìnrú gbèsè ṣì wọ́pọ̀ lónìí.[5][6]

  1. Jordan, Ann (February 2011). "SLAVERY, FORCED LABOR, DEBT BONDAGE, AND HUMAN TRAFFICKING: FROM CONCEPTIONAL CONFUSION TO TARGETED SOLUTIONS" (PDF). Program on Human Trafficking and Forced Labor. Washington College of Law: Center for Human Rights & Humanitarian Law. 
  2. 2.0 2.1 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named :0
  3. Global Report on Forced Labour in Asia: debt bondage, trafficking and state-imposed forced labour. International Labour Organization. 2005. http://www.ilo.org/global/about-the-ilo/newsroom/news/WCMS_075504/lang--en/index.htm. 
  4. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named Bales2004
  5. 5.0 5.1 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named :7
  6. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named :13