Jump to content

Ìsúlẹ̀ Òòrùn

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Isule Oorun

Ìsúlẹ̀ Òòrùn (solar eclipse) n sele nigbati Òsùpá ba gba arin ile-aye ati oorun koja ti o si di ile-aye loju patapata tabi die lati ri oorun.

Awon Iru Isule Oorun[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Isule patapata (total) n sele nigbati osupa ba di oju oorun patapata.
  • Isule oloruka (annular) n sele nigbati osupa ati oorun ba wa ni ori ila kanna ti oorun si han bi oruka.
  • Isule ajapo (hybrid) n sele larin isule patapata ati oloruka. Nibikan ni ori ile-aye o han bi isule patapata nibomiran bi isule oloruka. Isule ajapo kii fi be sele.
  • Isule eyidie (partial) n sele nigbati osupa ati oorun ko wa ni ori ila kanna, ti osupa si di oorun loju die.