Ìtẹ̀léntẹ̀lé Cauchy
Ìrísí
Ninu imo isiro, itelentele Cauchy, ti a s'oloruko fun Augustin Cauchy, je itelentele ti awon afida (element) re n sunmo ara won bi itelentele ohun ba se n po si. Ni soki, ti a ba jusile nomba pato afida lati ibere itelentele ohun, a le so ijinnasi togaju larin afida meji di kekere bo ba se wu wa.
Itelentele Cauchy fun awon nomba gidi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Itelentele kan,
fun nomba gidi je ti Cauchy, ti fun gbogbo nomba gidi alapaotun ti r > 0, nomba odidi N alapaotun yio wa fun won to je pe fun gbogbo awon nomba odidi m, n>N a ni
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |