Jump to content

Ìtọ̀

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Sample of human urine

Ìtọ̀ ni omi kan tí ó ń sun láti gbogbo oríkéríké ara tí ó sì gba inú kídìnrín lọ sínú àpò ìtọ̀ tàbí ilé ìtọ̀. Èyí ma ń wáyé nínú ara gbogbo ẹranko elégungun.[1] Jíjáde tàbí sísun omi ara tí kò wúlò fún àgọ́ ara mọ́ yí ni ó parapọ̀ tí ó di ìtọ̀ tí yóò sì gba ojú ara akọ tàbí abo jáde.[2]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Urine and Urination - Urine". MedlinePlus. 2020-01-14. Retrieved 2020-03-14. 
  2. "What Does Your Pee Say About You?". WebMD. 2019-01-30. Retrieved 2020-03-14.