Ìwé Àṣẹ Aṣàlàyé Ọ̀fẹ́ GNU

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
GNU Free Documentation License
Heckert GNU white.svg
Àmí ilé-iṣẹ́ GNU, gnu
Olùdákọ Free Software Foundation
Àtẹ̀jáde 1.3
Atẹ̀wéjáde Free Software Foundation, Inc.
Títẹ̀jáde Àtẹ̀jáde lọ́wọ́:
3 Oṣù Kọkànlá, odún 2008
Bíbámu mọ́ DFSG Bẹ́ẹ̀ni, láìsí abala kankan tó yàtọ̀
Atòlànà kọ̀mpútà ọ̀fẹ́ Bẹ́ẹ̀ni
Bíbámu mọ́ GPL Bẹ́ẹ̀kọ́
Copyleft Bẹ́ẹ̀ni

GNU Free Documentation License (GFDL) (Ìwé Àṣẹ Aṣàlàyé Ọ̀fẹ́ GNU) jẹ́ ìwé àṣẹ copyleft fún aṣàlàyé ọ̀fẹ́ látọwọ́ Free Software Foundation (FSF) fún àwọn iṣẹ́ ọwọ́ GNU. Àtẹ̀jáde 1.3 ni ó wà lọ́wọ́, ìkọ oníbiṣẹ́ rẹ̀ ṣe é rí ní àdírẹ́sì http://www.gnu.org/copyleft/fdl.html.

Ìwé àṣẹ náà wà fún aṣàlàyé atòlànà kọ̀mpútà àti bákanáà fún àwọn ìjésì míràn àti fún àwọn ìwé ìlànà. Èyí mudájú pé àwòkọ kọ̀ọ̀kan èlò náà, bótilẹ̀jẹ́ láláàtúnṣe, yíò ní ìwé àṣẹ kannáà. Àwọn àwòkọ wọ̀nyí ṣe é tà, sùgbọ́n eni tó tà gbọdọ̀ mọ̀ pé elòmíràn náà lè ṣe àtúnṣe síi láì gbàṣẹ lọ́wọ́ rẹ̀. Wikipedia ni iṣẹ́ ọwọ́ tótóbijùlọ aṣàlàyé ọ̀fẹ́ tó únlo ìwé àṣẹ yìí.


Àwọn ìjápọ̀ òde[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]