Jump to content

Ìyọkúrò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
"5 − 2 = 3" (pipe, "arun din ni eji dogba si eta")
An example problem

Ìyọkúrò ni ikan ninu ona ise isiro; idakeji re ni iropo, to tumo si pe ti a ba bere pelu nomba yiowu, ti a si seropo nomba kan ti a si tun seyokuro nomba kanna ti a ropo, a o pada de ori nomba ti bere pelu. Iyokuro se kosile pelu ami iyokuro.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ìròpọ̀ Ìyọkúrò Ìsọdipúpọ̀ Division
+ × ÷