Ìsọdipúpọ̀

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
3 × 4 = 12, a le to ami méjìlá sí orí ìlà gbọlọjọ mẹ́ta tí ikọ̀ọ̀kan ní àmìn mẹ́rin tàbí sí orí ìlà nínàró mẹ́rin tí ikọ̀ọ̀kan wọn ní àmìn mẹ́ta.
Àmì ìsọdipúpọ̀.

Ìsọdipúpọ̀ jẹ́ iṣẹ́ nínú mathematiki tó ń ṣe ìgbéga nọ́ḿbà kan pẹ̀lú òmíràn. Ó jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ọ̀nà ìṣirò mẹ́rin tó wa (àwon yioku ni ìròpọ̀, ìyọkúrò, àti pínpín). [1] Fún àwon nọ́mbà adaba ìsọdipúpọ̀ jẹ́ ìlọ́po tó ń yípo. Fún àpẹrẹ ìsọdipúpọ̀ 3 pẹ̀lú 4 (tàbí 3 lọ́nà 4) ṣẹ é ṣírò nípa ríro 3 mẹ́rin pọ̀ mọ́ ara wọn:
Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Boyer, Carl B. (2016-10-23). "A history of mathematics : Carl B. Boyer : Free Download, Borrow, and Streaming : Internet Archive". Internet Archive. Retrieved 2019-12-15. 
Symbol support vote.svg
Symbol oppose vote.svg
Symbol multiplication vote.svg
Symbol divide vote.svg
Ìròpọ̀ Ìyọkúrò Ìsọdipúpọ̀ Division
+ × ÷