Òògùn

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Oogun jẹ eyikeyi nkan, yato sí Óúnjẹ, ti ó sé lò fún itọju tabi imularada àìlera tàbí aìsàn. A lè lo oogun nipa fi fíi simu, di daje(gbí gbémì), abere ati béèbè lo.